Categories
Notes Yoruba

Akori Eko: Aranmo Ati Isinku

Aranmo ni agbara ti iro kan ni lori iro miiran eyi ti o le f ape ki iro mejeeji yi pada di iru kan naa tabi ki won fi abuda jo ara won lona miiran a le pe aranmo ni agbara ti iro kan ni lori miiran lati so di ni ara re. ki aranmo to le waye, oro meji gbodo fe gbe kegbe. Faweli yoo pari oro akoko faweli yoo si beere oro keji. Bi apeere.

            Ku + ile = kuule

            F1    F2

Iye ohun tabi silebu oro mejeeji ni o gbodo wa ninu ayo risi (oro aranmo). Apeere yii fihan pe faweli ‘I’ to bere oro keji ni gbogbo abuda faweli ‘u’ eyi si so faweli ‘I’ ati ‘y’.

IPO AFARANMO ATI IRO AGBARANMO

Iro afaranmo: eyi ni oro ti o ni agbara lati yi abudaa iro tabi die lara abuda iro miiran pada si tire.

Iro agbaranmo: iron i o yi pada ti o gba abudu iro miiran. Apeere:

            Ile + iwe           = ileewe

            Ara + ile           = araale

Iro faweli apeere oke ti o bere oro keji ninu apeere oke yii ni iro agbaranmo.

ORISII ARANMO

  1. Aranmo iwaju
  2. Aranmo eyin
  3. Aranmo alaiforu
  4. Aranmo aforo
  5. Aranmo kikun

1. ARANMO IWAJU: Eyi ni igba ti iro faweli ti o pari oro akoko ti o je iru afaranmo ba ran mo nro faweli ti o bere oro keyi ti ale to ka si gege bi iro agbaranmo. Bi apeere:

Iro afaranmoIro agberanmoAranmo iwaju
Ara+ ileRaale
Apo+ iyoApooyo
Owo+ iseOwoose
Etu+ ibonaetunbon
ile+ iweileiwe

2. ARANMO EYIN: Ni igba ti I n faweli ti o bere oro keyi ba ranmo iro faweli ti o pari oro akole. Apeere:

Iro afaranmoIro agbaranmoAranmo eyin
Ara+ okoAraooko
Ku+ aleKale
Omo+ okoomooko

3. ARANMO ALAIFORO: Eyi ni igba ti iro afaranmo ati iro agbaranmo ba tele ara won taa ra laije pe iro miiran jeyo laarin won. Bi apeere:

            Iya ile ====== iyaale

            Agba etu ====== agbeetu

            Ara eko ====== areeko 4. ARANMO AFORO: Ni igba ti iru miiran ba jeyo laarin iro faweli afaranmo ati iro faweli agbaranmo. Eyi wopo ninu ihun afomo ibere “ori” ati oro-oruko ninu eyi ti faweli ‘o’ ninu ‘oni’ ti maa n gbaranmo lara faweli ti o bere oro oruko konsonanti ‘n’ gbodo di ‘l’.

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version