Categories
Notes Yoruba

Akori Eko: Onka Yoruba (Egbaa De Aadota Oke)

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii:
Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi
2,000
4,000
6,000
8,000
10,000
12,000
14,000
16,000
18,000
20,000 Egbaa
Egbaaji
Egbaata
Egbaarin
Egbaarun-un
Egbaafa
Egbaaje
Egbaajo
Egbaasan-an
Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa
Igba lona ogun
Igba lona ogbon
Igba lona ogoji
Igba lona aadota
Igba lona ogota
Igba lona aadoje
Igba lona ogoje
Igba lona aadorun-un
Igba lona ogorun-un 2,000 x 1
2,000 x 2
2,000 x 3
2,000 x 4
2,000 x 5
2,000 x 6
2,000 x 7
2,000 x 8
2,000 x 9
2,000 x 10

E je ki a lo egbaa lati se onka nipa fifi egbaa pin iye onka ti a ba fe ka, ji a to maa kaa loke loke.
Onka Geesi Alaye ni Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba
30,000
32,000
34,000
36,000
38,000
42,000
44,000
46,000
48,000
52,000
54,000
56,000
58,000 2,000 x 15
2,000 x 16
2,000 x 17
2,000 x 18
2,000 x 19
2,000 x 21
2,000 x 22
2,000 x 23
2,000 x 24
2,000 x 26
2,000 x 27
2,000 x 28
2,000 x 29 Egbaa meedogun
Egbaa merindinlogun
Egbaa metafinlogun
Egbaa mejidinlogun
Egbaa mokandinlogun
Egbaa mokanlelogun
Egbaa mejilelogun
Egbaa metalelogun
Egbaa merinlelogun
Egbaa merindinlogbon
Egbaa metadinlogbon
Egbaa mejidinlogbon
Egbaa mokandinlogbon Egbaa lona meedogun
Egbaa lona merindinlogun
Egbaa lona metadinlogun
Egbaa lona mejidinlogun
Egbaa lona mokandinlogun
Egbaa lona mokanlelogun
Egbaa lona mejilelogun
Egbaa lona metalelogun
Egbaa lona merinlelogun
Egbaa lona merindinlogbon
Egbaa lona metadinlogbon
Egbaa lona mejidinlogbon
Egbaa lona mokandinlogbon

‘o din’ tabi ‘o le’ ni a o maa lotiti de ori onkaye ta a n fe. Bi apeere: 30,400 je egbaa meedogun o la irinwo, 51,000 ni egberundilogbon; 57,991 je egbaa mokandinlogbon o din mesan-an; 58,008 je egbaa mokandinlogbon o le mejo. Lati ori 20,000, a le wa ma aka oke bayii:
Onka Geesi Alaye ni Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba
40,000
60,000
80,000
100,000
120,000
140,000
160,000
180,000
200,000
220,000
240,000
260,000
280,000
300,000
400,000
500,000
600,000
800,000
1,000,000 20,000 x 2
20,000 x 3
20,000 x 4
20,000 x 5
20,000 x 6
20,000 x 7
20,000 x 8
20,000 x 9
20,000 x 10
20,000 x 11
20,000 x 12
20,000 x 13
20,000 x 14
20,000 x 15
20,000 x 20
20,000 x 25
20,000 x 30
20,000 x 40
20,000 x 50 Oke meji
Oke meta
Oke merin
Oke marun-un
Oke mefa
Oke meje
Oke mejo
Oke mesan-an
Oke mewaa
Oke mokanla
Oke mejila
Oke metala
Oke merinla
Oke meedogun
Ogun oke
Oke marundinlogbon
Ogbon oke
Ogoji oke
Aadota oke Oke lona meji
Oke lona meta
Oke lona merin
Oke lona marun-un
Oke lona mefa
Oke lona meje
Oke lona mejo
Oke lona mesan-an
Oke lona mewaa
Oke lona mokanla
Oke lona mejila
Oke lona metala
Oke lona merinla
Oke lona meedogun
Oke lona ogun
Oke lona marundinlogbon
Oke lona ogbon
Oke lona ogoji
Oke lona aadata

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii:

Onka GeesiOnka YorubaAlaye ni YorubaAlaye ni Geesi
2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan)Igba lona mewaa Igba lona ogun Igba lona ogbon Igba lona ogoji Igba lona aadota Igba lona ogota Igba lona aadoje Igba lona ogoje Igba lona aadorun-un Igba lona ogorun-un2,000 x 1 2,000 x 2 2,000 x 3 2,000 x 4 2,000 x 5 2,000 x 6 2,000 x 7 2,000 x 8 2,000 x 9 2,000 x 10

E je ki a lo egbaa lati se onka nipa fifi egbaa pin iye onka ti a ba fe ka, ji a to maa kaa loke loke.

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
30,000 32,000 34,000 36,000 38,000 42,000 44,000 46,000 48,000 52,000 54,000 56,000 58,0002,000 x 15 2,000 x 16 2,000 x 17 2,000 x 18 2,000 x 19 2,000 x 21 2,000 x 22 2,000 x 23 2,000 x 24 2,000 x 26 2,000 x 27 2,000 x 28 2,000 x 29Egbaa meedogun Egbaa merindinlogun Egbaa metafinlogun Egbaa mejidinlogun Egbaa mokandinlogun Egbaa mokanlelogun Egbaa mejilelogun Egbaa metalelogun Egbaa merinlelogun Egbaa merindinlogbon Egbaa metadinlogbon Egbaa mejidinlogbon Egbaa mokandinlogbonEgbaa lona meedogun Egbaa lona merindinlogun Egbaa lona metadinlogun Egbaa lona mejidinlogun Egbaa lona mokandinlogun Egbaa lona mokanlelogun Egbaa lona mejilelogun Egbaa lona metalelogun Egbaa lona merinlelogun Egbaa lona merindinlogbon Egbaa lona metadinlogbon Egbaa lona mejidinlogbon Egbaa lona mokandinlogbon

‘o din’ tabi ‘o le’ ni a o maa lotiti de ori onkaye ta a n fe. Bi apeere: 30,400 je egbaa meedogun o la irinwo, 51,000 ni egberundilogbon; 57,991 je egbaa mokandinlogbon o din mesan-an; 58,008 je egbaa mokandinlogbon o le mejo. Lati ori 20,000, a le wa ma aka oke bayii:

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
40,000 60,000 80,000 100,000 120,000 140,000 160,000 180,000 200,000 220,000 240,000 260,000 280,000 300,000 400,000 500,000 600,000 800,000 1,000,00020,000 x 2 20,000 x 3 20,000 x 4 20,000 x 5 20,000 x 6 20,000 x 7 20,000 x 8 20,000 x 9 20,000 x 10 20,000 x 11 20,000 x 12 20,000 x 13 20,000 x 14 20,000 x 15 20,000 x 20 20,000 x 25 20,000 x 30 20,000 x 40 20,000 x 50Oke meji Oke meta Oke merin Oke marun-un Oke mefa Oke meje Oke mejo Oke mesan-an Oke mewaa Oke mokanla Oke mejila Oke metala Oke merinla Oke meedogun Ogun oke Oke marundinlogbon Ogbon oke Ogoji oke Aadota okeOke lona meji Oke lona meta Oke lona merin Oke lona marun-un Oke lona mefa Oke lona meje Oke lona mejo Oke lona mesan-an Oke lona mewaa Oke lona mokanla Oke lona mejila Oke lona metala Oke lona merinla Oke lona meedogun Oke lona ogun Oke lona marundinlogbon Oke lona ogbon Oke lona ogoji Oke lona aadata

Bi a se n lo ‘o din’ ni kika egbaalegbaa naa ni a n lo ‘o din’ ati ‘o le’ ti a ba n ka lokeelokee. Bi apeere:

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
20,080 40,008 40,060 43, 000 47,000 49,000 51,000 55,000 57,000 59,00020,000+1 = 80 20,000+2 = 8 20,000×2 + 60 20,000×2 + 3,000 20,000×2 + 7,000 20,000×2 + 9,000 20,000×2 + 11,000 20,000×2 + 15,000 20,000×2 + 17,000 20,000×2 + 19,000Orin le l’oke kan Oke meji le mejo Otalelokee meji Oke meji le legbeedogun Oke meji le leeedegbaarin Oke meji le eedegbaarun-un Oke meji o le eedegbaafa Oke meji o le eegbaajo Oke meji o le eedegbaasan-an Oke meji le eedegbaawaaOke kan o le ogorin Oke meji ati eeyo mejo Oke meji o le ogota Oke meji ati egbeedogun Oke meji ati eedegbaarin Oke meji ati egbaarun-un Oke meji ati egbaafa o din egberun Oke meji ati edegbaajo Oke meji ati eedegbasan Oke meji ati eedegbawa

ISE AMUTILEWA

  1. Ko onka awon figo wonyi:
  2. 30,000
  3. 35,000
  4. 36,000
  5. 47,000
  6. 52,000
  7. 600,000
  8. 750,000
  9. 850,000
  10. 950,000
  11. 1,000,000

AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

OGUN

ITAN NIPA OGUN

Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii sugbon ada fadaka owo re se. Ogun ni a gbo wi pe o fi ada irin owo re la ona gberegede fun awon orisa yooku lati koja. Ise ribiribi ti ogun se yii ni awon orisa yii se fi jeoye Osin-Imole ni ile-Ife.

Itan fi han pe ode to ni okiki ni ogun. Tabutu ni oruko iya re. Baba re ni Ororinna. Won ni Ogun feran ise ode sise to bee to fi fi ilu sile lo si ori-oke kan ki o le ri aaye se ise ode. Igba ti ori-oke yii su un ni o pinnu lati pada si Ile-Ife. Igba ti ogun n bo, oju re le koko. Won ni:

                        ‘Ojo Ogun n ti ori oke e bo,

                        Aso ina lo mu bo ‘ra,

                        Ewu eje lo wo sorun’.

Eyi ti Ogun iba fi duro ni Ile-Ife, ilu Ire ni a gbo pe Ogun lo. Won si gba a tayotayo. A gbo pe emu ni Ogun ko beere nigba ti o de Ire. Won fun un ni ounje ati emu mu. Idi niyi ti won fi n so pe: ‘Ire ki i se ile Ogun, o yak i won nibe menu ni’. Ori oke ninu igbo kan ni Ogun tun lo do sin i Ire. Bi o ba n bow a si aarin ilu, mariwo ni o maa n fi bora. Idi niyi ti won fi n ki i ni: ‘O-laso-nile fimokimo bora, Mariwo yegbeyegbe laso ogun’.

Orisirisi oruko ni won n pe Ogun. Ogun ni won tun n pen i Lakaaye; Osinmole, Awoo, Olumokin, Yankanbiogbe ati bee bee lo.

IGBAGBO YORUBA NIPA OGUN

  • Ogun ni orisa to ni irin. Gbogbo awon ti won n fi irin se je ti ogun.
  • Oun lo la ona fun awon orisa elegbe re
  • Orisa to feran ododo ati otito
  • Orisa ogun ni Ogun
  • Gbenagbena ni Ogun

ODUN OGUN

Kari ile Yoruba ni won ti n se odun Ogun, sugbon o gbayi ju lo ni awon ilue bii Ondo, Ilesa, Ile-Ife, Akure ati Ekiti. Akoko isu titun ninu osu keje si ikejo odun ni won n se odun Ogun.Ilu Agere, Katakoto ati bembe ni ile Ogun.

AWON OHUN TI WON FI N BO OGUN

Aja, Esun isu, epo, adiye, agbo, ewure, eyele, igbin, ewa eyan, iyan, obi abata, orogbo, ataare ati emu. Eekan soso ni apaja ogun gbodo be aja ni orun ti won ba n bo Ogun.

OJUBO OGUN

Awon ohun ti a n ri ni ojubo orisa yii ni omo owu, opa ogun, emu sekele, ada, ibon,obe, irin, olugbondoro, awon nnkan ija ogun.

BI WON SE N BO OGUN

Bi won se n bo Ogun ilu naa ni won n bo Ogun idile kookan. Okuta ribiti lo duro fun Ogun Agbede. Ori re ni awon alagbede ti n ro oko ati ada. Irin wewe ti a ko jo sinu ate Ogun lo duro fun ‘Ogun Ate’.

ORIKI OGUN

                        Ogun lakaye. Osin Imole

                        Ogun alada meji

                        O fi okan san’ko

                        O fi okan ye’na.

                        Ojo ogun n ti ori oke bo

                        Aso ina l’o mu bora

                        Ewu eje lo wo.

                        Ogun onile owo, olona ola

                        Ogun onile kangunkangun orun

                        O pon omi s’ile f’eje we

                        Ogun awon l’eyinju’   

                        Egbe l’ehin omo kan,

                        Ogun meje l’ogun mi,

                        Ogun alara ni igba ‘ja,

                        Ogun Onire a gbagbo

                        Ogun ikola a gba’gbin

                        Ogun Elemona ni i gba esun’su

                        Ogun Aki’run a gba iwo agbo

                        Ogun Gbenagbena eran awun ni i je

                        Ogun Makinde ti d’Ogun l’ehin odi,

                        Bi ko ba gba Tapa, gb’Abooki,

                        Agba Uku-uku, agba Kemberi,

                        Nje nibo l’a ti pade Ogun?

                        A pade Ogun nibi ija,

                        A pade Ogun nibi ita;

                        A pade re nibi agbara eje n san,

                        Agbara eje ti i de ni lorun bi omi ago

                        Orisa t’o ni t’Ogun ko to nkan

                        A f’owo je’su re nigba aimoye…

ISE AMUTILEWA

  1. Ko onka awon figo wonyi:
    (i) 30,000
    (ii) 35,000
    (iii) 36,000
    (iv) 47,000
    (v) 52,000
    (vi) 600,000
    (vii) 750,000
    (viii) 850,000
    (ix) 950,000
    (x) 1,000,000
    AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA
    OGUN
    ITAN NIPA OGUN
    Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii sugbon ada fadaka owo re se. Ogun ni a gbo wi pe o fi ada irin owo re la ona gberegede fun awon orisa yooku lati koja. Ise ribiribi ti ogun se yii ni awon orisa yii se fi jeoye Osin-Imole ni ile-Ife.
    Itan fi han pe ode to ni okiki ni ogun. Tabutu ni oruko iya re. Baba re ni Ororinna. Won ni Ogun feran ise ode sise to bee to fi fi ilu sile lo si ori-oke kan ki o le ri aaye se ise ode. Igba ti ori-oke yii su un ni o pinnu lati pada si Ile-Ife. Igba ti ogun n bo, oju re le koko. Won ni:
    ‘Ojo Ogun n ti ori oke e bo,
    Aso ina lo mu bo ‘ra,
    Ewu eje lo wo sorun’.
    Eyi ti Ogun iba fi duro ni Ile-Ife, ilu Ire ni a gbo pe Ogun lo. Won si gba a tayotayo. A gbo pe emu ni Ogun ko beere nigba ti o de Ire. Won fun un ni ounje ati emu mu. Idi niyi ti won fi n so pe: ‘Ire ki i se ile Ogun, o yak i won nibe menu ni’. Ori oke ninu igbo kan ni Ogun tun lo do sin i Ire. Bi o ba n bow a si aarin ilu, mariwo ni o maa n fi bora. Idi niyi ti won fi n ki i ni: ‘O-laso-nile fimokimo bora, Mariwo yegbeyegbe laso ogun’.
    Orisirisi oruko ni won n pe Ogun. Ogun ni won tun n pen i Lakaaye; Osinmole, Awoo, Olumokin, Yankanbiogbe ati bee bee lo.
    IGBAGBO YORUBA NIPA OGUN
    (i) Ogun ni orisa to ni irin. Gbogbo awon ti won n fi irin se je ti ogun.
    (ii) Oun lo la ona fun awon orisa elegbe re
    (iii) Orisa to feran ododo ati otito
    (iv) Orisa ogun ni Ogun
    (v) Gbenagbena ni Ogun
    ODUN OGUN
    Kari ile Yoruba ni won ti n se odun Ogun, sugbon o gbayi ju lo ni awon ilue bii Ondo, Ilesa, Ile-Ife, Akure ati Ekiti. Akoko isu titun ninu osu keje si ikejo odun ni won n se odun Ogun.Ilu Agere, Katakoto ati bembe ni ile Ogun.
    AWON OHUN TI WON FI N BO OGUN
    Aja, Esun isu, epo, adiye, agbo, ewure, eyele, igbin, ewa eyan, iyan, obi abata, orogbo, ataare ati emu. Eekan soso ni apaja ogun gbodo be aja ni orun ti won ba n bo Ogun.
    OJUBO OGUN
    Awon ohun ti a n ri ni ojubo orisa yii ni omo owu, opa ogun, emu sekele, ada, ibon,obe, irin, olugbondoro, awon nnkan ija ogun.
    BI WON SE N BO OGUN
    Bi won se n bo Ogun ilu naa ni won n bo Ogun idile kookan. Okuta ribiti lo duro fun Ogun Agbede. Ori re ni awon alagbede ti n ro oko ati ada. Irin wewe ti a ko jo sinu ate Ogun lo duro fun ‘Ogun Ate’.
    ORIKI OGUN
    Ogun lakaye. Osin Imole
    Ogun alada meji
    O fi okan san’ko
    O fi okan ye’na.
    Ojo ogun n ti ori oke bo
    Aso ina l’o mu bora
    Ewu eje lo wo.
    Ogun onile owo, olona ola
    Ogun onile kangunkangun orun
    O pon omi s’ile f’eje we
    Ogun awon l’eyinju’
    Egbe l’ehin omo kan,
    Ogun meje l’ogun mi,
    Ogun alara ni igba ‘ja,
    Ogun Onire a gbagbo
    Ogun ikola a gba’gbin
    Ogun Elemona ni i gba esun’su
    Ogun Aki’run a gba iwo agbo
    Ogun Gbenagbena eran awun ni i je
    Ogun Makinde ti d’Ogun l’ehin odi,
    Bi ko ba gba Tapa, gb’Abooki,
    Agba Uku-uku, agba Kemberi,
    Nje nibo l’a ti pade Ogun?
    A pade Ogun nibi ija,
    A pade Ogun nibi ita;
    A pade re nibi agbara eje n san,
    Agbara eje ti i de ni lorun bi omi ago
    Orisa t’o ni t’Ogun ko to nkan
    A f’owo je’su re nigba aimoye…

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version