Categories
Yoruba

Atunyewo awon eya ara ifo

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara ba n soro, bi ariwo lasan no ohun ti won n so.

Ni aye atijo, awon baba-nla wa kii fi gbogbo enu soro. Won gba wi pe ‘gbogbo aso ko la n sa loorun’. Awon ona kan wa ti won n gba ba eni to sun mo won, to wa nitosi tabi ona jijin soro lai lo enu. Se “Asoku oro ni je omo mi gb’ena”. Won a maa lo eya ara tabi fi nnkan miiran paroko ranse si won, ti itumo ohun ti won soyoo si ye won.

Ni ode-oni ewe, irufe ona ibanisoro yii wa, bi o tile je wi pe ona igbalode ni won n gbe e gba. Gbogbo nnkan wonyi ni a o yewo finnifinni.

IBANISORO AYE ODE ONI

Ni ode-oni, ede ni opomulero ona ibanisoro. Ede ni a fi n se amulo agbara lati ronu ti a o si so ero inu wa jade fun agboye: ti a fi n salaye ohunkohun. Ohn ni a fi n ba ni kedun, ti a n fi n ban i yo, ohun ni a fi n ko ni lekoo ni ile ati ile-iwe. Ede ni a fi n gbani ni iyanju, ti a tun fi n danilaraya. Pataki ede ni awujo ko kere.

Bi ko bas i ede, redio, iwe iroyin ko le wulo. Ede ni redio ati telifison fi n danilaraya, ti won fi n ko ni lekoo, ti won fi n royin. Olaju esin ati ti eko imo sayensi ti mu aye lu jara nipa imo ero. Awon ona ibanisoro ode oni niwonyi:

  • Iwe Iroyin: Ipa pataki ni iwe iroyin n ko bii ona ibanisoro. Henry Town send ni o koko te “Iwe Iroyin fun awon Egba ati Yoruba” jade ni ede Yoruba ni odun 1859. Eyi ni iwe iroyin akoko ni ede Yoruba. Leyin re ni “Iwe Irohin Eko” ti A.M. Thomas je olootu re jade ni odun 1888. Odun 1891 ni Eni-owo J. Vernal gbe “Iwe Eko” jade. Eyi fi han wipe ojo iwe iroyin tip e ni ile Yoruba.
  • Telifison: Ile Yoruba naa ni Telifison akoko ni ile eniyan dudu ti bere ni ilu Ibadan. Bi oruko re “Ero-Amohun-Maworan” ni a n pe o. anfaani gbigbo oro ati riri aworan awon eniyan inu re wo je iranlowo ti ko ni afirwe ninu gbigbe ede ati asa Yoruba laruge. Ona kaan naa niyi ti a fi gbe ero eni si ori eto, ti ibanisoro si n waye.
  • Redio: Ojo redie naa tip e ni ile Yoruba. Bii oruko re ‘ero-asoromagbesi’, oro lasan ni a n ti won n so ni ori eto okan-o-jokan won. Anfaani wa fun eniyan lati gbe ero won si ori afefe lati fi danilaraya, ko ni lekoo, ni lekoo ati fi laniloye.
  • Pako Alarimole lebaa Titi ati Ina Adari-Oko: Awon patako alarimole wa kaakiri oju popo ti won n juwe tabi dari eni si opopona laarin ilu-nla-nla. Bee ni ina adari-oko wan i ojuu Popo ti won n dari oko. Awon meta ni awon fi n paroko lilo ati diduro oko ni ikorita. Awo pupa duro fun ‘duro’, ewu wa lona; awo olomi osan ni ki a si ina oko ni imura sile lati lo, bee ni awo ewe ni ki oko maa lo.
  • Ero-Aye-Lu-Jara: (Intaneeti). Ero ayelujara je gbagede agbaye to si sile fun teru-tomo, ti a le lo, to si wan i arowoto gbogbo eniyan.
  • Leta Kiko: Leta kiko je aroko aye atijo ni orisiirisii ona. Gbigbe ni a n gbe leta, gbigbe naa ni a n gbe aroko ti a ba di ni gbinrin, titu ni a n tu apo-iwe lata, titu naa ni an tu gbinrin ti a di, kika la n ka leta, wiwo ni a n ami aroko. Igba ti won bat u u ni won yoo to mo ohun to wa nibe.
  • Foonu: Oro naa ni a n so si inu foonu ti eni to wan i odikeji ti a pe n gbo. Bi oun naa ba fesi awa ti a pe naa yoo gbo. Ona ibanisoro yii di ilumoka ni ile Yoruba. A le wan i Eko, ki a ma takuroso pelu eni to wan i ilu Oyinbo!
  • Agogo: Bi o tile je pe agogo je ohun-elo iparoko aye atijo, won si n lo won bi ona ibanisoro ni ode-oni. Bi apeere:

Agogo ile isin lilu   –           lati pe eeyan wa josin ni soosi

Agogo omo ile wa –           lati fi pea won akekoo wole

Agogo onisowo      –           lati fi fa onibara won mora.

OSE KARUN-UN

AKORI EKO: ONKA YORUBA (EGBAA de AADOTA OKE)

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii:

Onka GeesiOnka YorubaAlaye ni YorubaAlaye ni Geesi
2,0004,0006,0008,00010,00012,00014,00016,00018,00020,000EgbaaEgbaajiEgbaataEgbaarinEgbaarun-unEgbaafaEgbaajeEgbaajoEgbaasan-anEgbaawaa (oke kan)Igba lona mewaaIgba lona ogunIgba lona ogbonIgba lona ogojiIgba lona aadotaIgba lona ogotaIgba lona aadojeIgba lona ogojeIgba lona aadorun-unIgba lona ogorun-un2,000 x 12,000 x 22,000 x 32,000 x 42,000 x 52,000 x 62,000 x 72,000 x 82,000 x 92,000 x 10

E je ki a lo egbaa lati se onka nipa fifi egbaa pin iye onka ti a ba fe ka, ji a to maa kaa loke loke.

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
30,00032,00034,00036,00038,00042,00044,00046,00048,00052,00054,00056,00058,0002,000 x 152,000 x 162,000 x 172,000 x 182,000 x 192,000 x 212,000 x 222,000 x 232,000 x 242,000 x 262,000 x 272,000 x 282,000 x 29Egbaa meedogunEgbaa merindinlogunEgbaa metafinlogunEgbaa mejidinlogunEgbaa mokandinlogunEgbaa mokanlelogunEgbaa mejilelogunEgbaa metalelogunEgbaa merinlelogunEgbaa merindinlogbonEgbaa metadinlogbonEgbaa mejidinlogbonEgbaa mokandinlogbonEgbaa lona meedogunEgbaa lona merindinlogunEgbaa lona metadinlogunEgbaa lona mejidinlogunEgbaa lona mokandinlogunEgbaa lona mokanlelogunEgbaa lona mejilelogunEgbaa lona metalelogunEgbaa lona merinlelogunEgbaa lona merindinlogbonEgbaa lona metadinlogbonEgbaa lona mejidinlogbonEgbaa lona mokandinlogbon

‘o din’ tabi ‘o le’ ni a o maa lotiti de ori onkaye ta a n fe. Bi apeere: 30,400 je egbaa meedogun o la irinwo, 51,000 ni egberundilogbon; 57,991 je egbaa mokandinlogbon o din mesan-an; 58,008 je egbaa mokandinlogbon o le mejo. Lati ori 20,000, a le wa ma aka oke bayii:

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
40,00060,00080,000100,000120,000140,000160,000180,000200,000220,000240,000260,000280,000300,000400,000500,000600,000800,0001,000,00020,000 x 220,000 x 320,000 x 420,000 x 520,000 x 620,000 x 720,000 x 820,000 x 920,000 x 1020,000 x 1120,000 x 1220,000 x 1320,000 x 1420,000 x 1520,000 x 2020,000 x 2520,000 x 3020,000 x 4020,000 x 50Oke mejiOke metaOke merinOke marun-unOke mefaOke mejeOke mejoOke mesan-anOke mewaaOke mokanlaOke mejilaOke metalaOke merinlaOke meedogunOgun okeOke marundinlogbonOgbon okeOgoji okeAadota okeOke lona mejiOke lona metaOke lona merinOke lona marun-unOke lona mefaOke lona mejeOke lona mejoOke lona mesan-anOke lona mewaaOke lona mokanlaOke lona mejilaOke lona metalaOke lona merinlaOke lona meedogunOke lona ogunOke lona marundinlogbonOke lona ogbonOke lona ogojiOke lona aadata

Bi a se n lo ‘o din’ ni kika egbaalegbaa naa ni a n lo ‘o din’ ati ‘o le’ ti a ba n ka lokeelokee. Bi apeere:

Onka GeesiAlaye ni GeesiOnka YorubaAlaye ni Yoruba
20,08040,00840,06043, 00047,00049,00051,00055,00057,00059,00020,000+1 = 8020,000+2 = 820,000×2 + 6020,000×2 + 3,00020,000×2 + 7,00020,000×2 + 9,00020,000×2 + 11,00020,000×2 + 15,00020,000×2 + 17,00020,000×2 + 19,000Orin le l’oke kanOke meji le mejoOtalelokee mejiOke meji le legbeedogunOke meji le leeedegbaarinhttps://googleads.g.doubleclick.net/pagead/ads?guci=2.2.0.0.2.2.0.0&client=ca-pub-1661929042807246&output=html&h=600&slotname=9757662299&adk=3275073759&adf=2424874615&pi=t.ma~as.9757662299&w=214&fwrn=4&fwrnh=100&lmt=1604143231&rafmt=1&psa=1&format=214×600&url=http%3A%2F%2Fstoplearn.com%2Fcourses%2Fsecondary-school%2Fss2-third-term-yoruba-language-senior-secondary-school%2Flessons%2Fatunyewo-awon-eya-ara-ifo%2F&flash=0&fwr=0&fwrattr=true&rpe=1&resp_fmts=4&wgl=1&adsid=ChEI8Jb0_AUQms_jh5KIqv7UARJFAA7JAC9D_r8jNU-9UGzyqF49nNTGR2Z9aXP3XInddzKv8aYC__S0DY0ykDFe_zI-_81D4mRlayf3_R7_j_Cr74GIX8f6&tt_state=W3siaXNzdWVyT3JpZ2luIjoiaHR0cHM6Ly9hZHNlcnZpY2UuZ29vZ2xlLmNvbSIsInN0YXRlIjowfSx7Imlzc3Vlck9yaWdpbiI6Imh0dHBzOi8vYXR0ZXN0YXRpb24uYW5kcm9pZC5jb20iLCJzdGF0ZSI6MH1d&dt=1604142847468&bpp=43&bdt=76&idt=166&shv=r20201029&cbv=r20190131&ptt=9&saldr=aa&abxe=1&cookie=ID%3D3b5c0a4b352ccd7b-2255262b41a60032%3AT%3D1602230088%3ART%3D1602230088%3AS%3DALNI_MaWUG7yiaaHthyGgrREyU5I0uWdRw&prev_fmts=0x0%2C1200x90_0ads_al&nras=1&correlator=3115808717162&frm=20&pv=1&ga_vid=1353998279.1604142848&ga_sid=1604142848&ga_hid=1348636999&ga_fc=0&iag=0&icsg=9597842620330&dssz=61&mdo=0&mso=0&u_tz=60&u_his=15&u_java=0&u_h=768&u_w=1366&u_ah=728&u_aw=1366&u_cd=24&u_nplug=3&u_nmime=4&adx=909&ady=718&biw=1518&bih=730&scr_x=0&scr_y=0&eid=21067981&oid=3&psts=AGkb-H8O8yqtjv9LN4H3rmFgrkUWi8l_iux1HKrgmywM1YekSILRw1zK_Q&pvsid=1491728200890001&pem=804&ref=http%3A%2F%2Fstoplearn.com%2Fcourses%2Fsecondary-school%2Fss2-third-term-yoruba-language-senior-secondary-school%2Flessons%2Fonka-yoruba%2F&rx=0&eae=0&fc=896&brdim=0%2C0%2C0%2C0%2C1366%2C0%2C1366%2C728%2C1517%2C730&vis=1&rsz=d%7C%7CaoEe%7C&abl=CA&pfx=0&fu=8320&bc=31&jar=2020-10-31-11&ifi=1&uci=a!1&fsb=1&xpc=BN5N0SdBWw&p=https%3A//stoplearn.com&dtd=MOke meji le eedegbaarun-unOke meji o le eedegbaafaOke meji o le eegbaajoOke meji o le eedegbaasan-anOke meji le eedegbaawaaOke kan o le ogorinOke meji ati eeyo mejoOke meji o le ogotaOke meji ati egbeedogunOke meji ati eedegbaarinOke meji ati egbaarun-unOke meji ati egbaafa o din egberunOke meji ati edegbaajoOke meji ati eedegbasanOke meji ati eedegbawa

ISE AMUTILEWA

  1. Ko onka awon figo wonyi:
  • 30,000
  • 35,000
  • 36,000
  • 47,000
  • 52,000
  • 600,000
  • 750,000
  • 850,000
  • 950,000
  • 1,000,000

AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

OGUN

ITAN NIPA OGUN

Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii sugbon ada fadaka owo re se. Ogun ni a gbo wi pe o fi ada irin owo re la ona gberegede fun awon orisa yooku lati koja. Ise ribiribi ti ogun se yii ni awon orisa yii se fi jeoye Osin-Imole ni ile-Ife.

Itan fi han pe ode to ni okiki ni ogun. Tabutu ni oruko iya re. Baba re ni Ororinna. Won ni Ogun feran ise ode sise to bee to fi fi ilu sile lo si ori-oke kan ki o le ri aaye se ise ode. Igba ti ori-oke yii su un ni o pinnu lati pada si Ile-Ife. Igba ti ogun n bo, oju re le koko. Won ni:

                        ‘Ojo Ogun n ti ori oke e bo,

                        Aso ina lo mu bo ‘ra,

                        Ewu eje lo wo sorun’.

Eyi ti Ogun iba fi duro ni Ile-Ife, ilu Ire ni a gbo pe Ogun lo. Won si gba a tayotayo. A gbo pe emu ni Ogun ko beere nigba ti o de Ire. Won fun un ni ounje ati emu mu. Idi niyi ti won fi n so pe: ‘Ire ki i se ile Ogun, o yak i won nibe menu ni’. Ori oke ninu igbo kan ni Ogun tun lo do sin i Ire. Bi o ba n bow a si aarin ilu, mariwo ni o maa n fi bora. Idi niyi ti won fi n ki i ni: ‘O-laso-nile fimokimo bora, Mariwo yegbeyegbe laso ogun’.

Orisirisi oruko ni won n pe Ogun. Ogun ni won tun n pen i Lakaaye; Osinmole, Awoo, Olumokin, Yankanbiogbe ati bee bee lo.

IGBAGBO YORUBA NIPA OGUN

  • Ogun ni orisa to ni irin. Gbogbo awon ti won n fi irin se je ti ogun.
  • Oun lo la ona fun awon orisa elegbe re
  • Orisa to feran ododo ati otito
  • Orisa ogun ni Ogun
  • Gbenagbena ni Ogun

ODUN OGUN

Kari ile Yoruba ni won ti n se odun Ogun, sugbon o gbayi ju lo ni awon ilue bii Ondo, Ilesa, Ile-Ife, Akure ati Ekiti. Akoko isu titun ninu osu keje si ikejo odun ni won n se odun Ogun.Ilu Agere, Katakoto ati bembe ni ile Ogun.

AWON OHUN TI WON FI N BO OGUN

Aja, Esun isu, epo, adiye, agbo, ewure, eyele, igbin, ewa eyan, iyan, obi abata, orogbo, ataare ati emu. Eekan soso ni apaja ogun gbodo be aja ni orun ti won ba n bo Ogun.

OJUBO OGUN

Awon ohun ti a n ri ni ojubo orisa yii ni omo owu, opa ogun, emu sekele, ada, ibon,obe, irin, olugbondoro, awon nnkan ija ogun.

BI WON SE N BO OGUN

Bi won se n bo Ogun ilu naa ni won n bo Ogun idile kookan. Okuta ribiti lo duro fun Ogun Agbede. Ori re ni awon alagbede ti n ro oko ati ada. Irin wewe ti a ko jo sinu ate Ogun lo duro fun ‘Ogun Ate’.

ORIKI OGUN

                        Ogun lakaye. Osin Imole

                        Ogun alada meji

                        O fi okan san’ko

                        O fi okan ye’na.

                        Ojo ogun n ti ori oke bo

                        Aso ina l’o mu bora

                        Ewu eje lo wo.

                        Ogun onile owo, olona ola

                        Ogun onile kangunkangun orun

                        O pon omi s’ile f’eje we

                        Ogun awon l’eyinju’   

                        Egbe l’ehin omo kan,

                        Ogun meje l’ogun mi,

                        Ogun alara ni igba ‘ja,

                        Ogun Onire a gbagbo

                        Ogun ikola a gba’gbin

                        Ogun Elemona ni i gba esun’su

                        Ogun Aki’run a gba iwo agbo

                        Ogun Gbenagbena eran awun ni i je

                        Ogun Makinde ti d’Ogun l’ehin odi,

                        Bi ko ba gba Tapa, gb’Abooki,

                        Agba Uku-uku, agba Kemberi,

                        Nje nibo l’a ti pade Ogun?

                        A pade Ogun nibi ija,

                        A pade Ogun nibi ita;

                        A pade re nibi agbara eje n san,

                        Agbara eje ti i de ni lorun bi omi ago

                        Orisa t’o ni t’Ogun ko to nkan

                        A f’owo je’su re nigba aimoye…

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version