Categories
Notes Yoruba JSSCE

Kika iwe asayan ti ijoba yan fun saa yii

Kika iwe asayan ti ijoba yan fun saa yii

Ayoka Ewi YORUBA LAKKOOTUN

IGBELEWON:

Ninu ewi  yorruba Lakotun   ko eko marun-un ti ewi naa ko e gege bii akeekoo

ISE ASETILEWA:

  • Ko eko marun ti imele akekoo ko e gege bi I akekoo

EKA ISE: EDE

ORI ORO: ISE AGBE

     Ise Agbe je kiko ati mimo nipa oko riro tabi dida

Ise Agbe je ise akoko se eda,gege bi a se ri I ninu Bibeli ninu iwe Genesiisi ori kin in ni ese                 .

      Awon to n pese ohun elo ti a n je ni a n pen i AGBE

OHUN ELO ISE AGBE NI AYE ATIJO ATI NI ODE ONI

  • Oko
  • Ada
  • Aake
  • Obe
  • Ero irole tabi iko ebe
  • Ero ktakata
  • Oogun ajile abbl

ORISI AGBE TI O WA

  1. AGBE ALAROJE: Iwonba oko fun atije ebi ni agbe alaroje maa n da.Awon ohun ogbin bii; isu ogede,agbado, ata,ati ewebe ni won maa n gbin. Ni gba miiran ti o ba seku ni won maa n ta loja
  2. AGBE ALADA-N-LA/OLOKO N-LA: Awon wonyi ni won n fi ise agbe se ise loju mejeeji.won a maa da oko nla bii; oko koko,oko roba,oko agbo,oko owu,oko obi,oko ope oyinbo,oko anamo,oko egusi abbl.

Agbe alada-n-la pin si ona meji.Awon niyi;

  • Agbe olohun ogbin: Awon ni o n gbin gbogbo ounje ti a n je kaari aye
  • Agbe olohun osin: Awon Agbe wonyi lo n sin oniruuru ohun osin bii; Aja,Ewure, Elede, Adiye, Ehoro, Oya, Eja, Igbin, Oyin abbl

IGBELEWON:

  • Fun ise Agbe ni oriki
  • Orisi agbe meloo ni o wa?
  • Salaye orisi agbe lekun un rere
  • Daruko awon ohun elo ise agbe laye atijo ati lode-oni

ISE ASETILEWA:

Ko ohun elo ise agbe laye atijo ati lode oni marun-un

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version