Categories
Yoruba

AKOTO EDE YORUBA

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: AKOTO EDE YORUBA

Akoto ni sipeli tuntun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati fi maa ko ede Yoruba sile.

Awon ayipada ti o de ba kiko ede Yoruba sile ni wonyi

SIPELI ATIJOSIPELI TUNTUNIFIYESI
Aiya Aiye EiyeAya Aye EyeA gbodo yo faweli “I” nitori a ko pe e
Otta Oshogbo Ogbomosho Ebute-MetaOta Osogbo Ogbomoso Ebute-MetaKonsonanti meji kii tele ara ninu ihun ede Yoruba
Olopa Alanu Lailai Na Papa Miran YiOlopaa Alaaanu Laelae Naa Paapaa Miiran YiiIye iro faweli ti a ba pe ni ki a ko sile
On Enia Okorin Obirin Nkan OnjeOun Eniyan Okunrin Obinrin Nnkan Ounje 
Tani Kini Gegebi Gbagbo Nitoripe Lehina BiotilejepeTa ni Kin ni Wi pe Gege bi Gba gbo Nitori pe Leyin naa Bi o tile jepeA ni lati ya awon oro yii soto

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: IWA OMOLUABI ATI ANFAANI RE

Omoluabi ni omo ti a bi ti a si ko ti o gba eko rere.

Ile ni a ti n ko eso rode. ise ati iwa omoluabi bere lati inu ile ti a ti bii.

Lara awon iwa omoluabi ni,

  1. Iwa ikini
  2. Bibowo ati titeriba fun agba
  3. Hihuwa pele lawujo
  4. Ooto sise
  5. Iwa irele ati suuru
  6. Iwa igboran
  7. Sise oyaye
  8. Iwa iran-ra-eni lowo.

Igbelewon:

  • Kin ni akoto?
  • Ko sipeli atijo mewaa ki o si ko akoto re gege bii awon onimo se so
  • Fun iwa omoluabi loriki
  • Ko iwa omoluabi marun-un ki o si salaye

Ise asetilewa: ko sipeli atijo mewaa ki o si salaye awon ayipada ti o de ba okookan won gege bi awon onimo se fi enu ko ni odun 1974

Exit mobile version