Categories
Yoruba

Aroko

Awon Yoruba ni awon ona ti won n gba ba ara won soro asiri ni atijo bi ati ile je pe eni ti won n so fun ko si nitori. Ami lasan ni won yoo fi ranse ti ami naa yoo si tumo ara re. Fifi ohun kan ranse bi ami lati fi aye pataki kan ye eni ti a fi ohun naa ranse sin i a n pen i aroko.
Aroko ni ami tabi ona ede ti o leje oro kan tabi ohun to duro fun nkan miiran ti a le lo lati fi ba ara eni soro lona ijinle eyi o fun wan i orisirisi itumo ti o yato si ohun ti ami naa je kii se gbogbo aroko ni a n fin ranse sin i. Awon aroko kan wa ti o je pe ibi ti yio ti rorun fun eni ti a n paroko si lati ti ri ni a n fi won si eyi yoo fun wa ni anfaani lati le tete ri.
ORISII AROKO
i. Aroko ikilo
ii. Aroko itonisona
iii. Aroko ikede
iv. Aroko ibawi
v. Aroko ti n fi ero inu eni han abbl
1. AROKO IKILO: Bi eniyan ba n huwa aito bii fife iyawo ile elo miiran, ole jija tabi huwa odaran tabi ika. Won le paroko ranse si iru eni bee ki o jawo tabi ki o wa toro aforiji laijebe won yoo fi ijiya ti oto si onitohun je e. Apeere:
AMI AROKO ITUMO AROKO
1. Ti won ba fi iye adiye si ehinkule okunrin Won n ki lo fun pe ki ojawo ninu ajosepo pelu obinrin olobinrin
2. Eso omo osan Eyi ti e ba se ni o dara
3. Ooya ti a fi n yanu Ipinya de
4. Efun Oye n bow a kan o
5. Ikarahun igbin Okan mi n fa si o
6. Eesan Iroyin buruku ni a n gbo ni pa re
7. Okuta kekere Ara wa lebi okuta
8. Awo ehoro Ki o yara ma salo
9. Igbo eyi nahun Ki a mu oro naa ni koko
10. Ogan ese adie Je ki a ni nnkan ti a o te
11. Ajoku owu Ami iku ni, ewu n be fun e
12. Oju eja Ki a ri nkan daju
13. Eluti afin re aro A ko ri imole nkan naa daadaa
14. Awe obi Oro naa pari patapata
15. Esuru Ora naa ti sun mi
16. Agbayun Adun ni oran meta
17. Owo/igbale A gba ese re kuro lako
18. Iyepe didi lewe ranse Ebe tabi imule ki eniyan ma dale
19. Kanikani tuntun ati ose Iyawo eni naa ti bimo tuntun
20. Fifi iye adie ranse Mo n reti re kiakia
21. Eyin aja ati osun Fi oro naa se soun fi raara (aja kii sa n omo re de eegun)

APEERE AROKO IKILO
AMI AROKO ITUMO AROKO
1. Eesan Eyi tumo sip e iroyin aburu ni won gbo si eni naa
2. Ti won ba fi irepe aso obinrin ati ada ranse si okunrin miran Ki okunrin naa jawo ninu ife ikoko pelu obinrin olobinrin
3. Ti ilu kan ba fi ata ati iyo ranse si ilu keji Won ti ni ikunsinu ara won tele ki won si ma mura ogun
4. Ti a ba fi esunsu ranse si eniyan Agbo pe eni naa fe dawo e le ohun kan ti ako fe ki o dawole, ki o jawo kiakia

AROKO ATONISONA: Aroko wonyi wa lati to eniyan sona ki a maa baa ko sinu ewu tabi isoro. A kii fi aroko yii ranse, ogangan ibi ti yio ti rorun fun eni ti aranse si lati ri ni an gbe won si. Apeere:
AMI AROKO ITUMO AROKO
1. Ti won ba fi eeru si ori ewe ni eba ona Ode kan wa nitosi ibe tabi pe o ti gba ibe koja
2. Ti won ba ta mariwo tabi aso si oju ona Enikeni ko gbodo gba oju ona naa koja nitori ewu wa nibe

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version