Pon – na ni ki oro tabi ifo niju itumo kan lo. Ti a ba fi oye oro awon oro tabi apola inu ede Yoruba finnifini an ri wipe awon oro kan wa ti won maa n ju itumo kan lo. Won le je eyo oro – oruko, oro – ise tabi akanlo – ede ti a dalo ninu gbolohun. Bi apeere:
- Tinu – tinu leje oruko bi apeere: Tinuade, Tinuola
Tinu – tun le tumo si ankan inu eran bi edo
- Odi – Mo ri odi kan laa naa
Odi – le tumo si eni to ko gboro
(fence) odi le tumo si ogiri ti a mo yii ilu ka
Odi – (boarder) o le tumo si enu ona ilu
- Ayo (name) Ayo Kosi nibe
Ayo (joy) Ayo ko si ninu ila naa
- Gun – o ti gun ri nnkan maa kuni
Gun – ki ewure sese ni oyun
- Mobuta – mo jeun
Ki a fi owo bu ata si inu nnkan kan
- Obawaja: Oba ilu kan
Oba ilumo inu orule ile
- Mojuba ehoro – mo sare tele
Mo fi owo fun ehoro
- Iya eye naa tide – igba to bi iya aje
Iya ti o je aje gan-an lode
- Ija aje naa ti de yato bi iya aje
Iya ti oje aye gan-an lode
- Omo Akin – Omo ti Akin bi
Akinkanju omo
Omo ise Akin
- Bola ti wo ileya – o ti dagba oti to pa eran odun ileya
Bolu ti to loko
- Won ta aso – ko ana aso sa si ibi kan
Ko eniyan gbe aso fun ni ki a ta
- A o ni polowo – a o ni polowo oja
- Nem keran – Yemi daran
Yemi keran – Yemi ji eran ko ninu ikoko iyare
- Gbeborun – Tayo gbe aso iborun iyagba
Gbeborun – Tayo se ofofo
- Ro – ki a fi nnkan si egbe kan
Ro – ki aso nnkan bi ala
Ise Asetilewa
Awon itumo wo ni a le fun oro tabi gbolohun yii:
- Baba gbese
- Wa oko gunle
- Ma towo bomi enu
- Ana ni ipari osu ojo ti ro
- Omo oja
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com