Ohun aimo (eyi ni ohun ti ko to, ohun ti ko wo, ohun ti ko ye) ti a ko gbodo se. Awon ohun ti asa esin ati ise wa ko gba laa ye lati se ni a n pe ni eewo. Yoruba bo won ni “eni ti o ba se ohun ti enikan o se ri, oju re a ri ohun ti enikan ko ri ri”.
Awon Yoruba kii fe dejaa eewo nitori won mo wipe eja a maa hun ni tabi fa ki ohun buburu sele si onitohun. Nigba miiran ohun buburu ti a lero le ma sele, sugbon ohun ti o se pataki ni eko ti won fe ko ni.
Bi eewo se wa fun agba, bee naa ni o wa fun omode ni ile Yoruba, eewo agbalagba lejo mo eewo esin ibile tabi ti molebi (idile) bee eewo awon ewe/omode wa lati ko omo lekooni ibamu pelu bi ironu ati ojo ori won se mo patakijulo, eewo je ona kan gbogi ti ori mu ki igbe aye alaafia ati ife joba ninu awon Yoruba.
ORISIRISI EEWO ILE YORUBA
- EEWO FUN IMOTOTO TABI OFIN ILERA
EEWO | OHUN TI YIO SELE | IDI TI O FI DI EEWO |
a. A ko gbodo fo aso ni ale | Iya eni naa yio ku | Ki aba le reran ri bi aso naa na mo tabi ko mo |
b. Ako gbodo to sinu odo | Bi eni naa ko ba mu omi aro yo ku | O le je odo ti won mu o si le fa aisan fun opolopo eniyan |
d. A ko gbodo jokoo ni enu ona jeun | Eni naa ko ni yo | Panti le gbon si ounje naa bi awon eniyan se n lo ati bo |
e. A ko gbodo je irun ori | Eni naa yio ku | Irun ori le doti o si le fa aarun si ago ara |
e. A kii ji te epo egusi mole | O sin i yio ta eni naa paX440x16 | Ki a le maa gba ile wa leyin ti a ba se egusi tan |
f. A kii fi igi owo dana | Eni naa yoo ku | Lati dekun awon eni ti n fi igi owo sina tabi sere |
g. A ko gbodo fi owo gbe ojo | Owo eni naa yio maa gbon | Lati dekun fifi owo ko idoti ati otutu |
gb. A ko gbodo fi ese te eyin tabi edo inu ibepe mo le | Eni naa yio ya aro | Ki a le maa ko eyin ibepe ati eso inu re danu nitori o le yon i subu |
- EEWO FUN ITONI (AKONILOGBON): Awon eewo ti o wa labe isori yii je eyi ti o le toni sona ti on aba daru tabi lati ko ni lekoo sise lodi si iru awon eewo bayii maa n mu ijiya kan tabi omiran lowo. Apeere:
EEWO | OHUN TI YIO SELE | IDI TI O FI DI EEWO |
a. A ko gbodo fo ile agbon | Awo ti eni naa ba n gbe, yio ma fo | Agbon le ta eniyan loju |
b. Omode ko gbodo fi igi fa ila sile | Iya omo naa yio ku | Ki igi naa ma ba gun ni ikun tabi oju |
d. A ko gbodo fi igbale naa omokunrin | Ikan omokurin re yio ku | O le wo oju ara re lo |
e. Omode ko gbodo mo obi re loju tabi naa obi re | Osi yio ta omo naa pa | Iwa aito ni |
e. Omo iya kannaa ko gbodo ba obirin kan lo po | Bi won ba see sit i igbonwon gba ara won nidii ounje eyi rgbon yio ku | Lati dekun iwa aito |
f. A ko gbodo naa alaboyun | Ki omo ti yio bi ma ban i apa dara | Ki a ma aba fi owo gba ni kun |
- EEWO FUN IGBEAYE ALAAFIA: Awon eewo yii wa fun imu larale ati igbe aye irorun. Apeere:
EEWO | OHUN TI YIO SELE | IDI TI O FI DI EEWO |
a. A ko gbodo ru idi igi gba arin tabi agbi ile koje | Eniyan kan yio ku ninu ile naa | Lati dekun ijamba fun awon ewe ti n sare kiri |
b. Okunrin ko gbodo fe obinrin tie se re koni koje gbin | Bi o ba fi esegbe ipanti wole, ile naa yoo di ahoro | Lati dekun iku ninu idele/ile |
d. Aboyun kogbodo dakun dele sun | Omo inu re le ku tabi ki o yaro | Oyun le tibe baje lara re |
e. Aboyun ko gbodo rin ni aru tabi ninu oorun osan gangan | Anjonu le le omo inu re jade ki osi wonu re lo | Lati dekun irin oru tabi osan fun won le ni ki won ta okuta mora |
e. Omo ko gbodo jabo leyin iya re | Bi o ba je obinrin, okunrin meta yio kun i ori re, bee gege ni okunrin naa | Ko awon abiyami maa mojuto awon omo won daradara |
f. A kii rorin ale | Oko tabi aya eni ti oba dan-an wo yoo kun | O le seeriejun eni ti o ba n sare bo ninu okunkun |
- EEWO IDILE: Inui tan orirun tabi oriki orile Yoruba ni opo eewo idile ti n suyo. Eewo idile le wa fun iyawo tabi omo – ile. Okookan eewo yii wa ye nitori iwa aidara ti won hu si eru-binrin nigba asiko isoro omo bibi
Idile / iran ati eewo
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com