Categories
Notes Yoruba

Ori Oro: Aroko – Aroko Ajemo-Isipaya

Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re

Aroko kiko ninu ede Yoruba gba ironu jinle,a ko le ko aroko sile lai je pe a fi oye ati ogbon inu ko o

Orisi aroko kiko

  1. Aroko onileta
  2. Aroko alalaye
  3. Aroko onisorogbesi
  4. Aroko asapejuwe
  5. Aroko alariyanjiyan
  6. Aroko oniroyin
  7. Aroko ajemo isipaya

AROKO AJEMO ISIPAYA

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye lekun-un-rere nipa nnkan ayika eni

Aroko yii je alaye kikun nipa ori oro kan,idi niyi ti o fi je pe akekoo ni lati ma aka iwe jona(journals), iwe iroyin(news papers) ,iwe ede iperi(dictionaries) ati awon iwe miiran ti yoo fun won ni imo kikun nipa ohun ti o n sele ni ayika won

Ori oro to jemo aroko ajemo isipaya

  • Ounje ile wa
  • Ise tisa
  • Imototo
  • Iwa lewa
  • Eko ile
  • Atelewo eni kii tan ni je
  • Iwa rere leso eniyan abbl

Igbelewon:

  • Kin ni aroko?
  • Ko orisi aroko ede Yoruba
  • Fun aroko ajemo-isipaya loriki
  • Ko ori oro marun-un ti o je mo aroko ajemo-isipaya

Ise asetilewa: Ko aroko ajemo isipaya lori ori “Imototo”

Exit mobile version