Categories
Notes Yoruba JSSCE

ORI ORO:  ASA IRAN-RA-ENI LOWO LAWUJO YORUBA

Asa iran-ra –eni lowo je ona ti awon yoruba n gba ran ara won lowo nibi ise won gbogbo

 Yoruba gbagbo ninu ki won se iranwo fun omonikeji. Won a maa ko ara jo lati da oko,koi le,ko ebe,kore oko,fo epo,gbe odo,la ona,gbe koto abbl. Ba kan naa,won a maa se iranlowo owo fun ara won nipa dida ajo, dida esusu ati kikorajopo lati da egbe alafowosowopo ode oni sile.

ORISI ONA TI YORUBA N GBA RAN ARA WON LOWO LAYE ATIJO

  • Ajo
  • Esusu
  • Ebese
  • Owe
  • Aaro
  • Arokodoko

IGBELEWON:

  • Salaye asa iran-ra-eni lowo ni soki
  • Daruko awon ona ti Yoruba n gba ran ara won lowo ni ile Yoruba

ISE ASETILEWA:

  • Salaye ona iranra-eni-lowo ode-oni ni kikun.
Exit mobile version