Categories
Notes Yoruba

Ori Oro : Isori Oro- Oro Ise

Oro ise ni koko fonran ti o n toka isele tabi nnkan ti oluwa se ninu gbolohun.

Oro ise ni opomulero gbolohun, lai si oro ise ninu gbolohun, ko le ni itumo.

Oro ise ni o maa n fun wa ni imo kikun nipa ohun ti oluwa se ninu gbolohun.

Orisi oro ise

  • Oro ise kikun
  • Oro ise agbabo
  • Oro ise alaigbabo
  • Oro ise asodidi gbolohun
  • Oro ise eleyo oro ise(ponbele)
  • Oro ise alakanpo
  • Oro ise elela
  • Oro ise alailela

Bi a se le lo awon oro ise wonyi ninu gbolohun ati bi a se le da won mo

  1. Oro ise kikun: Eyi ni eyo oro ise eyokan ti o ni itumo ninu gbolohun.apeere;
  2. Yemi sun
  3. Adufe jeun
  4. Folake korin
  5. Oro ise agbabo: Eyi ni oro ise ti won ko le sai gba abo(oro orruko) ninu gbolohun.apeere;
  6. Mo ra oko
  7. Anike ta ile
  8. Kilanko fe iyawo
  9. Oro ise alaigbabo: A kii lo  oro abo pelu oro ise yii.apeere;
  10. Olodumare dara
  11. Igbeyawo dun
  12. Alamu jo
  13. Oro ise asodidi gbolohun(oro apase):Awon oro yii maa n waye bii gbolohun ase bakan naa won le duro bii gbolohun.apeere;

Wa, jokoo, dide, jade

  • Oro ise alakanpo:  A le pe oro ise yiii ni ‘Asinpo’. Eyi ni ki oro ise to bii meji tabi ju bee lo ninu gbolohun.apeere;
  • Ole ko obe je
  • Ologbo pa eku je
  • Ige je ewa yo
  • oro ise elela:Eyi ni awon oro onisilebu meji sugbon ti a le la sim meji lati fi oro miiran bo o ni aarin ti a sit un le lo won ti a ko ba fi oro miiran bo o ni aarin.apeere;
  • Mo gba Oluwa gbo (Gbagbo) – mo gbagbo
  • Jesu gba baba naa la (gbala) – Jesu gbala
  • Esu tan Eefa je (tanje) – Esu tanje
  • Oro ise alailela: a ko le la awon oro ise wonyii si meji,odidi ni won maa n wa ninu gbolohun.apeere;
  • Fola subu lule
  • Oyindamola siwo ise
  • Bisola feran owo

Igbelewon:

  • Fun oro ise loriki
  • Ko orisi oro ti o wa ninu ede Yoruba
  • Salaye pelu apeere bi a se le lo awon oro ise wonyi ninu gbolohun.

Ise asetilewa:

  • Ko apeere oro ise alailela marun-un.

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version