Categories
Notes Yoruba

Oro Ayalo

Oro ayalo ni oro ti a ya lo lati inu ede kan wonu ede Yoruba tabi ede miiran ni ona ti pipe ati kiko re yoo fi wan i ibamu pelu batani iro ede ti a ya a wo. A n ya oro lati sapejuwe asa tuntun ti a n ba pade nipase owo sise, eto oselu, imo ero, imo sayensi, esin, eto amuluudun laarin awon ti won n so ede kan ati elde miiran. Ni Pataki oro ayalo maa n je ki ede kun si, ede ti ko bas i iyipada ninu re kii dagba.

Inu awon ede Yoruba ti ya awon oro lo niwonyi:

EDE                                          APEERE ORO TI A YA

Geesi                                       Buredi, fulawa, sikeeti, sitoofun, angeli, abbl

Hausa                                      Wahala, alaafia, mogaji, labara, alubosa, abbl

Feranse Larubawa                  Alubarika, mogarubi, alujoniu, mojesi, mekunnu abbl

Inu ede geesi ni Yoruba ti ya oro lo julo, idi abayo ni wi pe

1. Ajosepo ojo pipe ti wa laarin ijoba ile Geesi ati ile Naijiria: ati pe

2. Ede Geesi lo tun je ede ibara-eni-soro ni ile ise nibi apejo ati ni ile iwe

Batani ihun ede Yoruba ati oro ayalo

Awon oro ti a bay a wo inu ede Yoruba gbodo wan i ibamu pelu batani bi a ti se n ko awon iro ede Yoruba siel. Bi apeere:

  1. Konsonanti kii pari silebu tabi oro Yoruba
  2. Isupo konsonanti ko gbodo waye ninu ede Yoruba
  3. Gbogbo oro ayalo ni a gbodo fi ami ohun ori
  4. Ihun oro ayalo gbodo tele liana ipele koofo: kf tabi fkf
  5. Faweli aranmupe ko le je fi ninu oro onibatani

EDA ORO AYALO

Orisii ona ti a le gba ya oro lati inu ede kan wonu ede Yoruba ni:

a. Ilana Afetiya: eyi ni ki atele liana bi a se fi eti gbo bi oro ti dun tabi bi awon elede se n pe e. Bi apeere:

            Tailor – Telo

            Bible – Baibu

            Peter – Pita

            Esther – Esita abbl

b. Ilana Afojuya – oro ayalo afojuya ni awon oro ti a ya nipa tilele liana bi awon elede ti a ya won se n ko awon oro bee sile. Apeere

            Table – Tabili

            Milk – Milliki

            Bible – Bibeli

            Esther – Esiteri

            Peter – Peteru

Ise asetilewa

Ya awon oro isale yii wonu ede Yoruba

  1. School
  2. Contractor
  3. Plug
  4. Driver
  5. Starch
  6. Train
  7.  Class
  8. Brush
  9. Fali
  10. Film

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading

Exit mobile version