Akanlo ede ni awon ijinle oro ti itumo won farasin.
Akanlo Ede lorisirisi
- Eleyo oro
- Akoni/Akin – Akoni kan kii sojo loju ogun (Akikanju eniyan)
- Otelemuye – Awon otelemuye ti mu awon odaran naa lanaa (olopa inu)
- Dobode – dobode kan lasan ni o , o o ti mo ewa lounje ajesun (omugo)
- Oro ise
- Gbaradi – mura
- Fewo – jale
- Topinpin – wadi oro finnifinni
- Yari – binu
- Apola oro
- Fi enu ko – soro odi si eni ti o ju ni lo ti o si le ba te ni je
- Fi iru jona/fi ori fo ile agbon – fifa oran tabi wahala si ori ara eni
- Fi aga gbaga – di je
- Gbe iku ta – mu itiju kuro
- Fi mu finle – se iwadi
- Erin iyangi – erin ti ko ti okan wa
- Fa omo yo – yege
- Gbe odomi/wo gau – ko sinu wahala abbl.
Igbelewon:-
- Kin ni akanlo ede
- Ko itumo akanlo ede wayi ni ijule:- topinpin
Fin enu ko
Fi mu finde
Gbe iku ta
Ise Asetilewa :- ko itumo ijinle akanlo ede wonyi :-
- Ba ni je afoju ewure
- Na papa bora
- Eja n bakan
- Te oju aje mole
- Fi eje sinu tuto funfun jade.
Asa : Oge Sise Ii
Awotele Obinrin
- Agbeko: Eyi ni aso olowo meji teere ti won n wo si abe buba
- Tobi/Sinmi: Eyi ni aso olokun ribiti ti won n wo si abe iro, o maa n gun de orukun
- Komu: Eyi ni aso olowo teere meji ti won n wo lati bo oyan
Awotele Okunrin
- Singileeti: Won maa n wo si abe aso
- Pata: Won n wo si isale sokoto
Akiyesi : Aso wiwo ni olori oge sise
Igbelewo : (i) ko awotele obinrin meta (ii) ko awotele okinrin meji pere
Ise-Asetilewa:
Ko aroko lori “Oge sise laaarin awon Yoruba ni aye atijo dara ju ti aye ode oni lo”
Litireso: Kika iwe litireso ti ijoba yan
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com