EKA ISE: EDE
AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN).
Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro.
Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji;
- Iro ohun geere
- Iro ohun eleyoo
Iro ohun geere: Eyi ni iro ohun ti o duro ni ori silebu lai ni eyo rara.
Awon iro bee ni;
a. Iro ohun oke ( / ) – M
b. Iro ohun isale ( \ ) – D
d. Iro ohun aarin ( – ) – R
Apeere iro ohun oke – mimo
titi
jide
kola abbl.
Apeere iro ohun Isale – ogede
Isale
Iwa abbl
Apeere iro ohun aarin – rere
Igba
Akin abbl
Iro ohun eleyoo: Eyi ni iro ti o n yo lati ipo iro ohun tire lo si ipo iro ohun miiran.
Iro ohun eleyo meji ni o wa;
- Iro ohun eleyoo roke (V): eyi ni awon iro ohun ti a pe nigba ti a gbe ohun wa towa si isale lo si oke lee kan naa. Apeere
Olopaa – olopa
Paapaa – paapaa
Yii – yii
- Iro ohun eleyoo rodo (^): eyi ni awon iro ohun ti a pe nigba ti a gbe ohun wa lati oke lo si isale leekan naa. Apeere
Yoo – yoo
Naa – naa
Akiyesi: A kii lo ami ohun eleyooroke ati eleyorodo mo ninu akoto ede Yoruba ode oni.
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: AWON OWE TI O JE MO ASA YORUBA
Asa igbeyawo
- Ati gbeyawo ko to pon, owo obe lo soro
- Bi aya ba moju oko tan, alarina a yeba
Asa iran-ra-eni lowo
- Ajeje owo kan ko gberudori
- Ka fi owo we owo ni owo se I mo
- Ka ro so mo di, ka rodi maso, a ni ki idi sa ti ma gbofo
- Ko kunrin rejo, kobinrin paa, a ni ki ejo sa ti ma lo abbl.
EKA ISE: LITIRESO
AKOLE ISE: ITUPALE ASAYAN IWE ITAN AROSO APILEKO TI AJO WAEC/ NECO YAN
Igbelewon:
- Fun iro ede loriki
- Salaye pelu apeere isori iro ede Yoruba
- Ko owe ti o je mo asa igbeyawo ati asa iran-ra-eni-lowo
Ise asetilewa: ko apeere iro ohun eleyoo-rodo ati eleyoo-roke marun-un marun-un
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com