ODUN IGBEKO YORUBA-SS 1
ISE OOJO-SAA KIN-IN-NI
1. Atunyewo awon eya ara ifo
Atunyewo Eko ile- asa ikini
Atunyewo orisirisi eya litireso
2. Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Ise abinibi
Eko lori igbadun ti o wa ninu litireso alohun
3. Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Owe
Eko lori igbadun ti o wa ninu litireso alohun
4. Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Sise ounje awujo Yoruba
Ogbon itopinpin litireso ede Yoruba
5. Itesiwaju lori eko lori iro ede (iro ohun )
Awon owe ti o je mo asa yoruba
Itupale asayan iwe itan aroso ti ajo WAEC/NECO yan
6. Silebu
Awon owe ti o suyo ninu ise ati ise Yoruba
7. Akoto ede Yoruba
Iwa omoluabi ati anfaani re
8. Aroko kiko
Ise abinibi ile Yoruba
Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan.
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com