Categories
Notes Yoruba

SS2 3rd Term Yoruba Language scheme of work

THIRD TERM ILAANA ISE NI SAA KETA FUN SS2

 YORUBA LANGUAGE

OSEAKORI EKO
1EDE – Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya: Ilana ero aroko ajemo isipayaAkole, Ifaara, koko oro, agbalo gbdoAlaye kikun lori eto ipin afoKiko aroko lori akole bii Omi, Iyan,Oja ati bee lo ASA – Atunyewo lori eko ile: Ibowofagba, ikini, bi o se ye ni gbogbo igba, suuru, otito sise, iforiti, igboran ati bee bee lo LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan ti rgbe Akomolede fi owo si.
2EDE – Atunyewo lori silebu ede Yoruba: Oriki silebuSilebu oni faweli kan (F)Silebu alakanpo konsonanti ati faweliPipin oro si silebu ASA – Atunyewo ise abinibi: Ise agbe, gege bi ise abinibi gbogbo wa. Awon ohun elo ise agbe: Oko, Ada, ati bee bee loIse agbede, ise alapata, ise akope ati ise gbenagbena ati bee bee lo LITIRESO – Itesiwaju lori atupale awon iwe Litireso: Awon eda itanIbudo itan
3EDE – Atunyewo aroko onisorongbesi: Alaye lori oro onisorongbesiKiko aroko onisorongbesi to dale isele awujo ASA – Ona ibanisoro: Lilo awon eya ara fun ibanisoro bii sise ni ni eekanna, ori gbongbon, oju sise, ara mimi, titenimole, imu yinyin ati iparoko. LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati awon asa Yoruba to seyo ninu itan naa
4EDE – Atunyewo ihun oro Siseda oro roukoAlaye lori awon oro oruko ti a ko seda sugbon ti won dabi eyi ti aseda bi ile, oba, omo, iay ati bee bee lo ASA – Itesiwaju eko lori ona ibanisoro: Ibanisoro ni aye ode oni bi iwe iroyin, telifonu, redio, foonu, foonu alagbekaa 1 meeli ati fasi (fax) LITIRESO – Sise atupale asayan iwe litireso: Awon ilo ede/Akanlo edeSise orinkinniwin won
5EDE – Onka Yoruba: Lati egbaa de oke meedogbon on (2,000 – 500,000) ASA – Awon orisa ile Yoruba: Ogun, Obatala, EsuAwon ohun ti a fi n bo eon ati oriki okookan won LITIRESO – Kika iwe asayan ti ijoba yan
6EDE – Onka Yoruba: Lati oke meedogbon on de Aadota (500,000 – 1,000,000) ASA – Awon orisa ile Yoruba ati bi a se n bo won: Orunmila, SangoAwon ohun ti a fi n bo won ati oriki okookan won LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ajo WAEC/NECO yan
7EDE – Atunyewo awon eya ara ifo: Lilo awon eya ara ifoAlaye lori afipe asunsi ati afipe akanmole ASA – Awon orisa ati bi a se n bo won: Awon orisa miiran ni agbegbe awon akeekoIpo orisa ni ile YourbaPataki orisa lawujo Yoruba LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan
8EDE – Atunyewo awon iro ninu ede Yoruba: Iro faweli, iro konsonanti ati iro ohun ASA – Ero ati igbagbo awon Yoruba lori Oso ati Aje: Ise ti awon aje n se ninu isegun ati iwosan LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan
9.EDE – Atunyewo apejuwe iro konsonanti ati iro faweli: Yiya ate faweli ati konsonantiSise apejuwe awon iro konsonanti ati faweli leyo kookan ASA – Ero ati igbagbo Yoruba lori akudaaya ati abami eda: Akudaaya ati abami eda bii Egbere, Iwin, Alujonu, Ebora ati bee bee lo LITIRESO – Kikai we litireso ti ijoba yan
10EDE – Atunyewo eko lori ami ohun: Kiko ami ohun Yoruba meteetaAlaye lori ise ti ami ohun n se ninu ede Yoruba ASA – Igbagbo Yoruba nipa ori tabi eleeda: LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan fun saa yi
11 & 12Atunyewo lori gbogbo ise saa yii ati idanwo ipari saa keta lori Ede, Asa ati Litireso ede Yoruba

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com MAKE-MONEY

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading