Leta Aigbagbefe ni leta ti a ko si awon eniyan ti won wan i ipo kan ni ibi ise adaani tabi si ajo ilu. Leta bayii kii se si enikan pato, eniti o je oga ni asiko naa le kaa. Idi niyi ti a kii fi ko oruko eniyan kan si.
Ninu leta aigbagbefe, ko si aaye fun iroyin tabi efe rara. Apeere irufe leta yii ni n ko si Ajete, Olotuu iwe iroyin, Giwa ile-ise, Oba, Alaga igbimo, Alaga ijoba ibile, oga ile – iwe ati akowe agba ibi ise ijoba apapo bii oga agba ajo idanwi WAEC, NECO ati JAMB.
Igbese Leta aigbagbefe
Federal Government College,
Ilorin,
Kwara State.
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com 
Free Science simulations at Classadapt (UK) Classadapt.com
2nd February, 2015.
Olotuu,
Iwe Iroyin Alaroye
34, Agbabiaka Street,
Lagos.
Olotuu,
Oga ile – iwe,
Akowe agba, abbl
Ayeye Ojo Omiran Orile – Ede Naijiria.
Emi ni,
Biodun Agbabiaka.
(signature)
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com 
Free Science simulations at Classadapt (UK) Classadapt.com