Categories
Yoruba

EKO ILE- ASA IKINI

AKOLE ISE: EKO ILE- ASA IKINI

Eko ile ni eko iwa hihu: iwa rere, iwa to to, iwa to ye ti obi fi n ko omo lati kekere.

Eko ile je iwa omoluabi, ati kekere ni iru eko yii ti n bere ti yoo si di baraku fun omo titi ojo aye re.

Dandan ni fun omo lati mo bi ati n ki baba, iya ati awon miran ti o ju ni lo ni gbogbo igba.

Ikini akoko / igba.

 IGBA / AKOKOIKINI
IOjoEku  ojo / otutu
IiOyeEku oye
IiiIyanEku aheje kiri o
IvNi owuroEkaa oro
VNi osanEkaa san
ViNi iroleEeku irole
ViiNi oruEkuaajin

Ikini akoko Ise

 ISEIKINIIDAHUN
IAgbeAroko bodu de oAse
IiOnidiriOju gbooro, eku ewaIyemoja
IiiBabalawoAboru boye, sboye bo siseAmin
IvAwakoOko a re foo, goun a pana mo oAmin o
VAkopeIgba a ro oO o
ViOsise ijobaOko oba ko ni sa yin leseAse
ViiiIya olojaAje a wo gba oAse

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY