Categories
Yoruba

Ewo ile yoruba

Ohun aimo (eyi ni ohun ti ko to, ohun ti ko wo, ohun ti ko ye) ti a ko gbodo se. Awon ohun ti asa esin ati ise wa ko gba laa ye lati se ni a n pe ni eewo. Yoruba bo won ni “eni ti o ba se ohun ti enikan o se ri, oju re a ri ohun ti enikan ko ri ri”.

Awon Yoruba kii fe dejaa eewo nitori won mo wipe eja a maa hun ni tabi fa ki ohun buburu sele si onitohun. Nigba miiran ohun buburu ti a lero le ma sele, sugbon ohun ti o se pataki ni eko ti won fe ko ni.

Bi eewo se wa fun agba, bee naa ni o wa fun omode ni ile Yoruba, eewo agbalagba lejo mo eewo esin ibile tabi ti molebi (idile) bee eewo awon ewe/omode wa lati ko omo lekooni ibamu pelu bi ironu ati ojo ori won se mo patakijulo, eewo je ona kan gbogi ti ori mu ki igbe aye alaafia ati ife joba ninu awon Yoruba.

ORISIRISI EEWO ILE YORUBA

  1. EEWO FUN IMOTOTO TABI OFIN ILERA
EEWOOHUN TI YIO SELEIDI TI O FI DI EEWO
a. A ko gbodo fo aso ni aleIya eni naa yio kuKi aba le reran ri bi aso naa na mo tabi ko mo
b. Ako gbodo to sinu odoBi eni naa ko ba mu omi aro yo kuO le je odo ti won mu o si le fa aisan fun opolopo eniyan
d. A ko gbodo jokoo ni enu ona jeunEni naa ko ni yoPanti le gbon si ounje naa bi awon eniyan se n lo ati bo
e. A ko gbodo je irun oriEni naa yio kuIrun ori le doti o si le fa aarun si ago ara
e. A kii ji te epo egusi moleO sin i yio ta eni naa paX440x16Ki a le maa gba ile wa leyin ti a ba se egusi tan
f. A kii fi igi owo danaEni naa yoo kuLati dekun awon eni ti n fi igi owo sina tabi sere
g. A ko gbodo fi owo gbe ojoOwo eni naa yio maa gbonLati dekun fifi owo ko idoti ati otutu
gb. A ko gbodo fi ese te eyin tabi edo inu ibepe mo leEni naa yio ya aroKi a le maa ko eyin ibepe ati eso inu re danu nitori o le yon i subu
  1. EEWO FUN ITONI (AKONILOGBON): Awon eewo ti o wa labe isori yii je eyi ti o le toni sona ti on aba daru tabi lati ko ni lekoo sise lodi si iru awon eewo bayii maa n mu ijiya kan tabi omiran lowo. Apeere:
EEWOOHUN TI YIO SELEIDI TI O FI DI EEWO
a. A ko gbodo fo ile agbonAwo ti eni naa ba n gbe, yio ma foAgbon le ta eniyan loju
b. Omode ko gbodo fi igi fa ila sileIya omo naa yio kuKi igi naa ma ba gun ni ikun tabi oju
d. A ko gbodo fi igbale naa omokunrinIkan omokurin re yio kuO le wo oju ara re lo
e. Omode ko gbodo mo obi re loju tabi naa obi reOsi yio ta omo naa paIwa aito ni
e. Omo iya kannaa ko gbodo ba obirin kan lo poBi won ba see sit i igbonwon gba ara won nidii ounje eyi rgbon yio kuLati dekun iwa aito
f. A ko gbodo naa alaboyunKi omo ti yio bi ma ban i apa daraKi a ma aba fi owo gba ni kun
  1. EEWO FUN IGBEAYE ALAAFIA: Awon eewo yii wa fun imu larale ati igbe aye irorun. Apeere:
EEWOOHUN TI YIO SELEIDI TI O FI DI EEWO
a. A ko gbodo ru idi igi gba arin tabi agbi ile kojeEniyan kan yio ku ninu ile naaLati dekun ijamba fun awon ewe ti n sare kiri
b. Okunrin ko gbodo fe obinrin tie se re koni koje gbinBi o ba fi esegbe ipanti wole, ile naa yoo di ahoroLati dekun iku ninu idele/ile
d. Aboyun kogbodo dakun dele sunOmo inu re le ku tabi ki o yaroOyun le tibe baje lara re
e. Aboyun ko gbodo rin ni aru tabi ninu oorun osan ganganAnjonu le le omo inu re jade ki osi wonu re loLati dekun irin oru tabi osan fun won le ni ki won ta okuta mora
e. Omo ko gbodo jabo leyin iya reBi o ba je obinrin, okunrin meta yio kun i ori re, bee gege ni okunrin naaKo awon abiyami maa mojuto awon omo won daradara
f. A kii rorin aleOko tabi aya eni ti oba dan-an wo yoo kunO le seeriejun eni ti o ba n sare bo ninu okunkun
  1. EEWO IDILE: Inui tan orirun tabi oriki orile Yoruba ni opo eewo idile ti n suyo. Eewo idile le wa fun iyawo tabi omo – ile. Okookan eewo yii wa ye nitori iwa aidara ti won hu si eru-binrin nigba asiko isoro omo bibi

Idile / iran ati eewo

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com MAKE-MONEY

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading