Categories
Yoruba

Oro onapon-na

Pon – na ni ki oro tabi ifo niju itumo kan lo. Ti a ba fi oye oro awon oro tabi apola inu ede Yoruba finnifini an ri wipe awon oro kan wa ti won maa n ju itumo kan lo. Won le je eyo oro – oruko, oro – ise tabi akanlo – ede ti a dalo ninu gbolohun. Bi apeere:

  1. Tinu – tinu leje oruko bi apeere: Tinuade, Tinuola

Tinu – tun le tumo si ankan inu eran bi edo

  1. Odi – Mo ri odi kan laa naa

Odi – le tumo si eni to ko gboro

(fence) odi le tumo si ogiri ti a mo yii ilu ka

Odi – (boarder) o le tumo si enu ona ilu

  1. Ayo (name) Ayo Kosi nibe

Ayo (joy) Ayo ko si ninu ila naa

  1. Gun – o ti gun ri nnkan maa kuni

Gun – ki ewure sese ni oyun

  1. Mobuta – mo jeun

Ki a fi owo bu ata si inu nnkan kan

  1. Obawaja: Oba ilu kan

Oba ilumo inu orule ile

  1. Mojuba ehoro – mo sare tele

Mo fi owo fun ehoro

  1. Iya eye naa tide – igba to bi iya aje

Iya ti o je aje gan-an lode

  1. Ija aje naa ti de yato bi iya aje

Iya ti oje aye gan-an lode

  1. Omo Akin – Omo ti Akin bi

Akinkanju omo

Omo ise Akin

  1. Bola ti wo ileya – o ti dagba oti to pa eran odun ileya

Bolu ti to loko

  1. Won ta aso – ko ana aso sa si ibi kan

Ko eniyan gbe aso fun ni ki a ta

  1. A o ni polowo – a o ni polowo oja
  1. Nem keran – Yemi daran

Yemi keran – Yemi ji eran ko ninu ikoko iyare

  1. Gbeborun – Tayo gbe aso iborun iyagba

Gbeborun – Tayo se ofofo

  1. Ro – ki a fi nnkan si egbe kan

Ro – ki aso nnkan bi ala

Ise Asetilewa

Awon itumo wo ni a le fun oro tabi gbolohun yii:

  1. Baba gbese
  2. Wa oko gunle
  • Ma towo bomi enu
  1. Ana ni ipari osu ojo ti ro
  2. Omo oja

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com MAKE-MONEY

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading