kini-apeere-oro-oruko-oni-silebu-kan-ko-ki-n-se-oro-aropo-oruko-o

All QuestionsCategory: Secondary Schoolkini-apeere-oro-oruko-oni-silebu-kan-ko-ki-n-se-oro-aropo-oruko-o
ìkẹ́olúwa asked 2 years ago

Before using this website, you must read our disclaimer here.

3 Answers
Loveth answered 2 years ago

Before using this website, you must read our disclaimer here.

Ni bayii, e je ki a se agbeyewo awon oro (part of speech) inu eko girama ede Yoruba.

A. Oro-oruko ni oro ti n toka eniyan, eranko, ohun abemi, ohun aibemi, aridimu ati airidimu.

Apeere oro-oruko ni
(1) Aina sun
(2) Ilara wa nibi gbogbo
(3) Eye n ke
 
Source: https://olukoni.blogspot.com/2018/09/isori-oro-part-of-speech.html