Oran dida ati ijiya ti o da

All QuestionsCategory: Secondary SchoolOran dida ati ijiya ti o da
Biodun bolarinwa to asked 3 years ago

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY

1 Answers
Loveth answered 3 years ago

Laye atijo ko si ofin ti a ko sile gege bi ti ode – oni. Sugbon, a no awon asa, eewo, ilana ti awon agba fi n se eto agbo ile ati akoso ilu. Bi o tile je pe ako ni akosile ofin naa gege bi a ti nii ninu iwe ofin lode oni, ole jija, ipaniyan, alonilowogba, ifipa – jale, ati iwa buburu gbogbo ti a n tun ri lode oni, ko to bee po rara.
Source: https://stoplearn.com/oran-dida-ati-ijiya-ti-o-to/

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY