YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSSTWO
YORUBA JSSTWO
ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI
1. Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba
Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni
Atunyewo awon ewi alohun yoruba
2. Eya gbolohun nipa ise won
Asa igbeyawo ni ile Yoruba
Kika iwe apileko ti ijoba yan
3. Eya gbolohun
Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni)
Kika iwe apileko oloro geere
4. Gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o
Sise akanse ise awujo Yoruba (project)
Litireso alohun to je mo ayeye
5. Onka Yoruba (101-300)
Ise akanse kan ni awujo (project)
Litireso alohun to je mo ayeye
Kika iwe apileko ti ijoba yan
6. Onka Yoruba (300-500)
Sise itoju oyun ni ona abinibi ati ode-oni
7. Akaye oloro geere
Ise omo bibi (oro idile baba olomo)
Kika iwe apileko ti ijoba yan
8. Akaye oloro geere
Asa isomoloruko
Kika iwe apileko ti ijoba yan
9. Akoto
Igbagbo Yoruba nipa orisirisi owe ile Yoruba
Kika iwe apileko oloro geere ti ijoba yan
10. Kiko Yoruba ni ilana akoto ode-oni
Orisirisi oruko ile Yoruba (igbagbo Yoruba nipa abiku)
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com