Categories
Notes Yoruba

SS3 2nd Term Yoruba Language scheme of work

SECOND TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3

YORUBA LANGUAGE

OSEAKORI EKO
1EDE – Atunyewo eko kikun lori silebu ede Yoruba ASA – Atunyewo eko lori Elegbejegbe, iro-si-iro LITIRESO – Agbeyweo asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan Onkowe, eda itan ati awon amuye inu itan yii
2EDE – Atunyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba B.A foniimu konsonanti, faweli, ohun, konsonanti aranmupe, asesilebu Eda foniimu, konsonanti ati faweli ASA – Agbeyewo awon orisa ile Yoruba Obatala, Orunmila/Ifa. Itan ni soki nipa awon Aworo Orisa LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan
3EDE – Atunyewo eko lori oro ayalo minu oro ayalo wo inu ede Yoruba ASA – Atunyewo eko lori eko ebi ati iserun eni LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan
4EDE – Atunyewo kikun lori eko ihun oro ai iseda oro-oruko ASA – Atunyewo kikun lori ede eto iselu abinibi ati ode-oni LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan
5EDE – Atunyewo eko lori isori oro; oro oruko, oro aropo oruko, aoro aropo afarajoruko, oro ise ASA – Atunyewo eko lori oge sise, aso wiwo, itoju ara, ila kiko abbl. LITIRESO – Atunyewo eko lori alo apamo, apagbe ati itandowe abbl
6EDE – Atunyewo eko lori isori ori apejuwe, oro aponle, oro asopo ati oro atokun ASA – Atunyewo kikun lori asa igbeyawo ni ile Yoruba LITIRESO – Itupale Asayan iwe ti ajo WAEC/NECo yan

Read our disclaimer.

AD: Take Free online baptism course: Preachi.com MAKE-MONEY

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading