Categories
Notes Yoruba

IYATO TI O WA LARIN ORO APONLE ATI APOLA APONLE

Oro aponle je eyo oro kan ninu ihun gbolohun ti o maa n pon oro – ise. Ise re gan-an ni lati se afihan itumo fun apola ise ninu gbolohun. Bi apeere:

(i) Tunde rin: (ii) Tunde rin jaujau

Tunde rin kemokemo

Tunde rin pelepele

Gholohun (i) je oro ise alaigbagbo (rin) ko I oro aponle eyi ti yoo je ki a mo bi oluwa se rin. Sugbon awon iso/oro abo gbolohun (ii) ni oro aponle to se afikun itumo oro-ise β€œrin” ni ekunrere.

APOLA APONLE: Apola aponle je akojopo oro to n sise gege bi idi kan ti o si n pon oro-ise inu iso. Bi apeere: Ilu Osoosa maa n kun ni akoko odun agemo.

Orisirisi apola aponle

Apola aponle alasiko –  eyi n fi igba tabi asiko isele han. Bi apeere:

            Imole n mo nigba osan

            Okunkun n su nigba oru

            Ojo maa n po ni asiko ojo

Apola aponle orubii –  eyi maa n toka si ibi kan pato nin afo gbolohun. Bi apeere:

            Ile oduduwa wa ni Ile – Ife

            O ti ile bere wahala

            Oke giga wan i Efon

Apola aponle onidii: Eyi ni o maa n so idi nka pato. Bi apeere:

            O kole nitori omo

            A n sise nitori owo

            O kekoo ko le di eniyan pataki

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY