Ki ni Aroko?
Ko se e ma ni ni aroko kiko (essay writing), idi abajo si ni
pe o maa n fi han bi iriri ati ogbon atinuda akekoo se rinle si. Yato si eyi,
aroko kiko tun maa n je ki a mo bi akekoo se ni oye to nipa kiko ero okan re
sinu iwe.
Aroko alariyanjiyan je ona ti a n gba gbe ero totun – tosi kale, tii a si wadi ero naa nipa fifi ero eni han lori koko ero bee. Ona meji ni a le gba gbe aroko yii kale.
A le koko so ero wa si otun naa ki a to wa so si osi. Ni ona keji, a le so si otun, ki a tun so si osi. Ohun ti o se Pataki ninu aroko alariyanjiyan ni wi pe a ko gbodo dari apa kan fi kan sile.
Aroko alariyanjiyan je eyi ti o fun akekoo ni anfaani lati
se afiwe ori-oro meji lati fi han eyi ti o fara mo ni pato. O se Pataki fun
akekoo lati ma fari apa kan dakan si.
Apeere Ori-Oro Fun Aroko Alariyanjiyan:
- Ile-eko adani san ju ile-eko ijoba (wascce may/jun 2003)
- Ise adani lowo lori ju ise ijoba lo. (wascce may/jun 2005)
- Omi wulo ju ina monamona lo. (ssce may/jun 2011)
- Owo ni a fi n saye. (wascce nov/dec 2001)
- Esin ti dowo lorile-ede yii. (wassce may/jun 2013)
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com