Aroko (essay) loriileekomi

All QuestionsCategory: Secondary SchoolAroko (essay) loriileekomi
Olawepo kehinde asked 1 year ago

Aroko (essay) loriileekomi

Join Discussion Forum and do your assignment: Find questions at the end of each lesson, Click here to discuss your answers in the forum

Ad: Get a FREE Bible: Find true peace. Click here to learn how you can get a FREE Bible.

For advert placement/partnership, write ask@stoplearn.com

Download our free Android Mobile application: Save your data when you use our free app. Click picture to download. No subscription. stoplearn

We are interested in promoting FREE learning. Tell your friends about Stoplearn.com. Click the share button below!

1 Answers
Loveth answered 1 year ago

Ki ni Aroko?
Ko se e ma ni ni aroko kiko (essay writing), idi abajo si ni
pe o maa n fi han bi iriri ati ogbon atinuda akekoo se rinle si. Yato si eyi,
aroko kiko tun maa n je ki a mo bi akekoo se ni oye to nipa kiko ero okan re
sinu iwe.
Aroko alariyanjiyan je ona ti a n gba gbe ero totun – tosi kale, tii a si wadi ero naa nipa fifi ero eni han lori koko ero bee. Ona meji ni a le gba gbe aroko yii kale.
A le koko so ero wa si otun naa ki a to wa so si osi. Ni ona keji, a le so si otun, ki a tun so si osi. Ohun ti o se Pataki ninu aroko alariyanjiyan ni wi pe a ko gbodo dari apa kan fi kan sile.
Aroko alariyanjiyan je eyi ti o fun akekoo ni anfaani lati
se afiwe ori-oro meji lati fi han eyi ti o fara mo ni pato. O se Pataki fun
akekoo lati ma fari apa kan dakan si.
Apeere Ori-Oro Fun Aroko Alariyanjiyan:

  • Ile-eko adani san ju ile-eko ijoba (wascce may/jun 2003)
  • Ise adani lowo lori ju ise ijoba lo. (wascce may/jun 2005)
  • Omi wulo ju ina monamona lo. (ssce may/jun 2011)
  • Owo ni a fi n saye. (wascce nov/dec 2001)
  • Esin ti dowo lorile-ede yii. (wassce may/jun 2013)

Join Discussion Forum and do your assignment: Find questions at the end of each lesson, Click here to discuss your answers in the forum

Ad: Get a FREE Bible: Find true peace. Click here to learn how you can get a FREE Bible.

For advert placement/partnership, write ask@stoplearn.com

Download our free Android Mobile application: Save your data when you use our free app. Click picture to download. No subscription. stoplearn

We are interested in promoting FREE learning. Tell your friends about Stoplearn.com. Click the share button below!

Your Answer

14 + 9 =