SECOND TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3
YORUBA LANGUAGE
OSE | AKORI EKO |
1 | EDE – Atunyewo eko kikun lori silebu ede Yoruba ASA – Atunyewo eko lori Elegbejegbe, iro-si-iro LITIRESO – Agbeyweo asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan Onkowe, eda itan ati awon amuye inu itan yii |
2 | EDE – Atunyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba B.A foniimu konsonanti, faweli, ohun, konsonanti aranmupe, asesilebu Eda foniimu, konsonanti ati faweli ASA – Agbeyewo awon orisa ile Yoruba Obatala, Orunmila/Ifa. Itan ni soki nipa awon Aworo Orisa LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan |
3 | EDE – Atunyewo eko lori oro ayalo minu oro ayalo wo inu ede Yoruba ASA – Atunyewo eko lori eko ebi ati iserun eni LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan |
4 | EDE – Atunyewo kikun lori eko ihun oro ai iseda oro-oruko ASA – Atunyewo kikun lori ede eto iselu abinibi ati ode-oni LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan |
5 | EDE – Atunyewo eko lori isori oro; oro oruko, oro aropo oruko, aoro aropo afarajoruko, oro ise ASA – Atunyewo eko lori oge sise, aso wiwo, itoju ara, ila kiko abbl. LITIRESO – Atunyewo eko lori alo apamo, apagbe ati itandowe abbl |
6 | EDE – Atunyewo eko lori isori ori apejuwe, oro aponle, oro asopo ati oro atokun ASA – Atunyewo kikun lori asa igbeyawo ni ile Yoruba LITIRESO – Itupale Asayan iwe ti ajo WAEC/NECo yan |
Read our disclaimer.
AD: Take Free online baptism course: Preachi.com