Aroko je ona ti awon baba nla wa fi n ba ara won soro bi iru oro bee ba je oro asiri ti eni ti a fe ba so o ko sin i itosi. Aroko ni ami tabi ona ede ti o le je a fe ba so o ko si ni itosi. Aroko ni ami tabi ona ede ti o le je oro kan tabi ohun kan to duro fun nnkan miiran ti a le lo lati fi ba ara eni soro lona ijinle eyi ti o n fun wan i orisii itumo ti o yato si ohun ti ami naa je.
Aroko nii se itumo ara re eni ti a fi ran kii tun soro lori re. A le fi aroko ran eniyan si eni ti yoo paa ki o ma si mo titi ti onitohun yoo fi se ohun ti aroko naa ni ki o se. Bi o ti se je ese ti o ga pe ki a ja leta ti a fi ran ni si eniyan, bee gege ni o je ese ti o ga ki a ja aoko ti a fi ran ni si elomiran.
Ona ti a le pin aroko si:
- Aroko ibawi
- Aroko ikede
- Aroko ikilo
- Aroko Atonisona
- Aroko ti o n fi ero inu eni han
- Aroko elebe
- Orisii ona miiran ti a tun fi n paroko ni:
- Aale pipa (b) Oga fifa (d) Asewele
AMI AROKO | ITUMO WON |
1. Eso omo osan | Eyi ti e ba se ni o dara |
2. Ooya iyarun | Ipinya de |
3. Efun | Oye n bo wa kan o |
4. Ikarahun igbin | Okan mi n fa si o |
5. Eesan | Iroyin buruku ni a n gbo nipa re |
6. Okuta kekere | Ara wa le bi okuta |
7. Awo ehoro | Ki o yara maa sa lo |
8. Igba eyin ahun | Ki a mu oro naa ni koko |
9. Oju eja | Ki a ri nkan daju daadaa |
10. Ajoku owu | Ami iku ni, ewu n be fun e |
11. Fifi iye adie ranse | Mo n reti re kiakia |