Categories
Notes Yoruba

AWON ISERUN ENI (AWON BABA NLA ENI)

Nigbakuugba ti a ba menuba awon iserun eni awon eni igbaani to se awon eniyan kan sile ni a n tokasi. Bi a ba si menubaawon iserun, awon to ti ku ni a n tokasi pelu kii se alaaye. Bi baba ati iya to bi ni ba ku, iserun eni ni awon mejeeji, bi o ba si je pe baba ati iya to bi awon obi wa naa ba si ti ku iserun eni ni awon naa. Bee ni a le maa tan an titi de ori eni to te agbo ile tabi eni to se idile tabi iran kan sile. Iserun eni ni eni to se orile iran eni sile nigba laelae.

Oju orori loori se pataki ni ile Yoruba. Oju oori ni ibi ti a sin oku si. Igbagbo Yoruba ni pe gbogbo igba ti a ba pe oku ni oju oori re, yoo dahun yoo si se ohun ti a ba  fe.

Idi ti a fi gbagbo ninu awon iserun eni:

a. Ija pipari ni oju oori

b. Iranlowo jade kuro ninu isoro (B.A ti aje ba ri foro emi eni ti won si fe run agbo ile). Airomobi, abiku.

d. Lati tu won loju (bibe won ki won wa ya si odo won)

Ona ti a n gba tu won loju

a. Odun egungun

b. Odun oro (etutu ni asiko ogbele)

d. Odun eyo

e. Odun eje

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY

Discover more from StopLearn

Subscribe now to keep reading and get access to the full archive.

Continue reading