Categories
Notes Yoruba

SS3 1st Term Yoruba Language scheme of work

FIRST TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3

YORUBA LANGUAGE

OSEAKORI EKO
1EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa LITIRESO – Agbeyewo iwe ti Ajo WAEC/NECO yan. Onkowe, itan ni soki ati awon amuye miiran
2EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise. ASA – Eto ogunjije. Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
3EDE – Itesiwaju lori ihun oro Dida oro oruko ti asede mo yato si eyi ti a ko seda Itupale oro oruko eniyan, sise akojopo oro oruko ASA – Itesiwaju eko lori Egbe Awo Orisirisii egbe Awo ti o wa nile Yoruba Alaye kiku lori ipa ti awon egbe wonyii n ko ninu eto oselu LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
4EDE – Iba Isele (Aseranwo oro-ise) Orisii iba isele to wa Asetan, Aterere, Aisetan abblAwon wunreni ti o toka iba isele ninu gbolohun ASA – Itesiwaju eko nipa igbagbo ati ero Yoruba nipa oso ati aje. Ero ati igbagbo awon eya miiran ni orile ede Naijiiria ati orile ede miiran nipa oso ati aje LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
5EDE – Itesiwaju lori Oro Agbaso Yiyo oro enu oloro si oro agbaso, fifi eti si sise, kika ati jijabo iroyin ipade Yiya afo agba oro si afo-asafo ASA – Itesiwaju lori Eko ile ati imototo itoju ara, bi a se nkini, oro siso, onje jije ati awo fifo LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
6EDE – Itesiwaju lori oro aroko oniroyin, ijiroro kikun lori awon ori oro to je mo aroko oniroyin. Kiko ilapa ero ASA – Itesiwaju eko lori ojuse eni ni awujo pataki ojuse eni ninu ile, laarin ebi, egbe, adugbo, abbl LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
7EDE – Iyato to wa laarin Oro Aponle ati Apola Aponle, alaye kikun. Oro Aponle ati Apola Aponle, titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun, fifa oro aponle ati apola aponle yo ninu gbolohun tabi ipinro, sise alaye ise okookan won ninu gbolohun. Alopo mejeeji ninu gbolohun ASA – Itesiwaju lori oran dida ati ijiya ti o to ipa ti awon agbefoba ati agbonfinro n ko ninu sise eto idajo fun arufin ati odaran, orisii eto idajo ati oan ti a o gba fi iya je odaran laye atijo ati ode oni LITIRESO – Ayewo finifini lori awon Asayn itandowe. Itandowe siso, itandowe kookan ni oloro geere titoba si oew ati asa to suyo ninu itan kookan, isowolo ede ninu itan to di owe kookan.
8EDE – itesiwaju ninu aayan ogbufo. Ogbon ti a n ta fun aayan ogbufo lati ede geesi si ojulowo ede Yoruba. Fifoye itumo ayoka oloro geere to ta koko jut i ateyinwa lo lati inu ede geesi si ojulowo Yoruba ajumolo ASA – Itesiwaju nipa igbagbo awon Yoruba si aseyin waye ati abami eda LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
9.EDE – Itesiwaju Akaye Ayoka (orisirisi, agbeyewo orisirisi, akaye bii oloro geere, ewi, ere onitan, ati orisii ayoka danra wo ASA – Itesiwaju lori eewo. Awon eewo ti aisan mu wa akojopo aisan ati eewo ti alaisan kookan ko gbodo deja, anfaani awon eewo fun awon alaisan LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
10EDE – Atunyewo awon isori oro-oruko, oro aropo oruko, oro ise, sise itupale gbolohun kekere si isori oro ASA – Itesiwaju lori oruko ile Yoruba, oruko Amutorunwa, oruko abiso ati oriki inagije LITIRESO –  Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
11Atunyewo eko lori ise saa yii ninu ede, asa ati litireso
12Akanse idanwo lori eko, ede, asa ati litireso

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY