Categories
Notes Yoruba Yoruba JSSCE

JSS1 1st Term Yoruba scheme of work

YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 1

SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI

  1. Alifabeeti ede Yoruba

Itan isedale Yoruba

Oriki litireso

  • Ami ohun lori awon faweeli ati oro onisilebu kan

Ile-ife saaju dide oduduwa

  • Ami ohun

Awon eya Yoruba ati ibi ti won tedo si

Awon ohun to ya litireso soto si ede ojoojumo

  • Silebu

Ikini ni aarin eya Yoruba, ounje won ati bi won se n se won

  • Akoto ode oni

Ikini II Akoko

Litireso alohun to je mo Aseye

  • Akoto awon oro ti a sunki

Iwulo Ede Yoruba

Litireso Alohun to je mo esin

  • Onka Yoruba lati ookan de aadota (1-50)

Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba

Litireso Apileko

  • Onka lati ookan lelaadota de ogorun-un (51-100)

Asa ati ohun-elo isomoloruko

  • Oriki ati liana kiko aroko Yoruba pelu apeere

Isomoloruko II

Awon litir//so Apileko – Ere onitan.

  • Aroko atonisona Alapejuwe

Oye jije ati ohu elo oye jije

Awon litireso apileko ewi

  • Isori oro +ninu gbolohun

Isinku nile Yoruba

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY